ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 9
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù nínú iṣẹ́ àpọ́sítélì (1-27)

        • “O ò gbọ́dọ̀ di ẹnu akọ màlúù” (9)

        • ‘Mo gbé tí mi ò bá wàásù!’ (16)

        • Mo di ohun gbogbo fún gbogbo èèyàn (19-23)

        • Bí a ṣe lè kíyè sára nínú eré ìje ìyè (24-27)

1 Kọ́ríńtì 9:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 9:3-5; 1Kọ 15:7, 8

1 Kọ́ríńtì 9:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk, “àṣẹ.”

1 Kọ́ríńtì 9:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mú arábìnrin tó jẹ́ ìyàwó.”

  • *

    Wọ́n tún ń pè é ní Pétérù.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 19:11
  • +Mt 13:55; Ga 1:19
  • +Jo 1:42

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 16

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1996, ojú ìwé 20

1 Kọ́ríńtì 9:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 13:2

1 Kọ́ríńtì 9:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 20:6; Owe 27:18

1 Kọ́ríńtì 9:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 25:4; 1Ti 5:18

1 Kọ́ríńtì 9:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:26, 27; Ga 6:6; Flp 4:15-17

1 Kọ́ríńtì 9:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “àṣẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 18:3; 20:34; 2Tẹ 3:7, 8
  • +2Kọ 6:3; 11:7

1 Kọ́ríńtì 9:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 6:14, 16; Nọ 18:30, 31; Di 18:1

1 Kọ́ríńtì 9:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 10:9, 10; Lk 10:7, 8

1 Kọ́ríńtì 9:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 18:3; 20:34; 1Kọ 4:11, 12; 2Tẹ 3:8
  • +2Kọ 11:8-10

1 Kọ́ríńtì 9:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 3:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    8/8/2001, ojú ìwé 24

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    9/15/1996, ojú ìwé 17-18

1 Kọ́ríńtì 9:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 2:7; Ef 3:1, 2; Kol 1:25

1 Kọ́ríńtì 9:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹ̀tọ́.”

1 Kọ́ríńtì 9:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 16:3; 18:18
  • +Iṣe 21:24, 26

1 Kọ́ríńtì 9:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 13:34; Ga 6:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    9/1/1996, ojú ìwé 14-19

    12/15/1991, ojú ìwé 6

1 Kọ́ríńtì 9:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:1; 15:1; 2Kọ 11:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2005, ojú ìwé 27-31

1 Kọ́ríńtì 9:23

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 19:26; 1Tẹ 2:8

1 Kọ́ríńtì 9:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 10:22; Flp 3:14; 2Ti 4:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2011, ojú ìwé 16, 24

    5/1/2004, ojú ìwé 29

    10/1/1999, ojú ìwé 18

    8/1/1992, ojú ìwé 13-15

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 149

1 Kọ́ríńtì 9:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Gbogbo eléré ìdárayá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 2:5
  • +Jem 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 149

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2004, ojú ìwé 29-30

    10/15/2003, ojú ìwé 18-21

    10/1/2002, ojú ìwé 30

    1/1/2001, ojú ìwé 30-31

    10/1/1999, ojú ìwé 18, 20

    8/1/1992, ojú ìwé 15-17

1 Kọ́ríńtì 9:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 2:2; Flp 2:16; Heb 12:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2016, ojú ìwé 9

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    1/2012, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2002, ojú ìwé 31

    8/1/1992, ojú ìwé 17-18

    7/1/1992, ojú ìwé 28-29

1 Kọ́ríńtì 9:27

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fìyà jẹ ara mi; bá ara mi wí lọ́nà líle.”

  • *

    Tàbí “ẹni ìtanù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:13; Kol 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2013, ojú ìwé 14

    8/1/1992, ojú ìwé 18

Àwọn míì

1 Kọ́r. 9:1Iṣe 9:3-5; 1Kọ 15:7, 8
1 Kọ́r. 9:5Mt 19:11
1 Kọ́r. 9:5Mt 13:55; Ga 1:19
1 Kọ́r. 9:5Jo 1:42
1 Kọ́r. 9:6Iṣe 13:2
1 Kọ́r. 9:7Di 20:6; Owe 27:18
1 Kọ́r. 9:9Di 25:4; 1Ti 5:18
1 Kọ́r. 9:11Ro 15:26, 27; Ga 6:6; Flp 4:15-17
1 Kọ́r. 9:12Iṣe 18:3; 20:34; 2Tẹ 3:7, 8
1 Kọ́r. 9:122Kọ 6:3; 11:7
1 Kọ́r. 9:13Le 6:14, 16; Nọ 18:30, 31; Di 18:1
1 Kọ́r. 9:14Mt 10:9, 10; Lk 10:7, 8
1 Kọ́r. 9:15Iṣe 18:3; 20:34; 1Kọ 4:11, 12; 2Tẹ 3:8
1 Kọ́r. 9:152Kọ 11:8-10
1 Kọ́r. 9:16Isk 3:18
1 Kọ́r. 9:17Ga 2:7; Ef 3:1, 2; Kol 1:25
1 Kọ́r. 9:20Iṣe 16:3; 18:18
1 Kọ́r. 9:20Iṣe 21:24, 26
1 Kọ́r. 9:21Jo 13:34; Ga 6:2
1 Kọ́r. 9:22Ro 14:1; 15:1; 2Kọ 11:29
1 Kọ́r. 9:23Iṣe 19:26; 1Tẹ 2:8
1 Kọ́r. 9:24Mt 10:22; Flp 3:14; 2Ti 4:7, 8
1 Kọ́r. 9:252Ti 2:5
1 Kọ́r. 9:25Jem 1:12
1 Kọ́r. 9:26Ga 2:2; Flp 2:16; Heb 12:1
1 Kọ́r. 9:27Ro 8:13; Kol 3:5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 9:1-27

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

9 Ṣé mi ò lómìnira ni? Ṣé èmi kì í ṣe àpọ́sítélì ni? Ṣé mi ò rí Jésù Olúwa wa rí ni?+ Ṣé ẹ kì í ṣe iṣẹ́ ọwọ́ mi nínú Olúwa ni? 2 Ká tiẹ̀ ní mi ò jẹ́ àpọ́sítélì fún àwọn ẹlòmíì, ó dájú hán-ún pé mo jẹ́ bẹ́ẹ̀ fún yín! Nítorí ẹ̀yin ni èdìdì tó jẹ́rìí sí i pé mo jẹ́ àpọ́sítélì nínú Olúwa.

3 Ohun tí mo fi gbèjà ara mi lọ́dọ̀ àwọn tó ń wádìí mi wò nìyí: 4 A ní ẹ̀tọ́* láti jẹ àti láti mu, àbí a kò ní? 5 A ní ẹ̀tọ́ láti máa mú ìyàwó tó jẹ́ onígbàgbọ́*+ lẹ́yìn bíi ti àwọn àpọ́sítélì yòókù àti àwọn arákùnrin Olúwa + àti Kéfà,*+ àbí a kò ní? 6 Àbí ṣé èmi àti Bánábà+ nìkan ni kò ní ẹ̀tọ́ láti fi iṣẹ́ tí a fi ń gbọ́ bùkátà sílẹ̀ ni? 7 Ọmọ ogun wo ló ń ná owó ara rẹ̀ sórí iṣẹ́ tó ń ṣe? Ta ló ń gbin ọgbà àjàrà tí kì í jẹ èso rẹ̀?+ Àbí ta ló ń ṣe olùṣọ́ àgùntàn agbo ẹran tí kì í jẹ lára wàrà agbo ẹran náà?

8 Ṣé èrò èèyàn ló mú kí n sọ àwọn nǹkan tí mò ń sọ ni? Ṣé Òfin kò sọ bákan náà ni? 9 Torí ó wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin Mósè pé: “O ò gbọ́dọ̀ di ẹnu akọ màlúù nígbà tó bá ń pa ọkà.”+ Ṣé ti àwọn akọ màlúù ni Ọlọ́run ń rò ni? 10 Àbí torí wa ló ṣe sọ ọ́? Nítorí tiwa ló ṣe wà lákọsílẹ̀, torí ó yẹ kí ẹni tó ń túlẹ̀ àti ẹni tó ń pa ọkà máa retí pé wọ́n á pín nínú rẹ̀.

11 Tí a bá fúnrúgbìn nǹkan tẹ̀mí láàárín yín, ṣé ó pọ̀ jù ni tí a bá kórè nǹkan tara lọ́dọ̀ yín?+ 12 Tí àwọn míì bá ní ẹ̀tọ́ yìí lórí yín, ṣé èyí táwa ní kò ju tiwọn lọ fíìfíì ni? Síbẹ̀, a ò lo ẹ̀tọ́*+ yìí, àmọ́ à ń fara da ohun gbogbo ká má bàa dènà ìhìn rere nípa Kristi lọ́nàkọnà.+ 13 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé àwọn ọkùnrin tó ń ṣe iṣẹ́ mímọ́ máa ń jẹ àwọn nǹkan tẹ́ńpìlì àti pé àwọn tó ń ṣiṣẹ́ nídìí pẹpẹ máa ń gba ìpín nídìí pẹpẹ?+ 14 Lọ́nà yìí pẹ̀lú, Olúwa pàṣẹ pé kí àwọn tó ń kéde ìhìn rere máa jẹ nípasẹ̀ ìhìn rere.+

15 Àmọ́ mi ò tíì lo ìkankan nínú àwọn ìpèsè yìí.+ Ní tòótọ́, mi ò ṣe àkọsílẹ̀ àwọn nǹkan yìí torí kí a lè ṣe wọ́n fún mi, torí ó sàn kí n kú ju kí n jẹ́ kí ẹnì kan gba ẹ̀tọ́ tí mo ní láti ṣògo!+ 16 Ní báyìí, tí mo bá ń kéde ìhìn rere, kì í ṣe ohun tí mo lè máa fi ṣògo, nítorí dandan ni fún mi. Ní tòótọ́, mo gbé tí mi ò bá kéde ìhìn rere! + 17 Tí mo bá ń ṣe é tinútinú, èrè wà fún mi; síbẹ̀ tí kò bá ti inú mi wá, iṣẹ́ ìríjú kan ṣì wà ní ìkáwọ́ mi.+ 18 Kí wá ni èrè mi? Òun ni pé nígbà tí mo bá ń kéde ìhìn rere, kí n lè máa kéde rẹ̀ láìgba owó, kí n má bàa ṣi àṣẹ* tí mo ní lórí ìhìn rere lò.

19 Bó tiẹ̀ jẹ́ pé mi ò sí lábẹ́ ẹnì kankan, mo fi ara mi ṣe ẹrú gbogbo èèyàn, kí n lè jèrè ọ̀pọ̀ èèyàn tí mo bá lè jèrè. 20 Nítorí àwọn Júù, mo dà bíi Júù, kí n lè jèrè àwọn Júù;+ nítorí àwọn tó wà lábẹ́ òfin, mo dà bí ẹni tó wà lábẹ́ òfin, bó tiẹ̀ jẹ́ pé èmi fúnra mi ò sí lábẹ́ òfin, kí n lè jèrè àwọn tó wà lábẹ́ òfin.+ 21 Nítorí àwọn tó wà láìní òfin mo dà bí aláìní òfin, bó tiẹ̀ jẹ́ pé mi ò wà láìní òfin sí Ọlọ́run, àmọ́ mo wà lábẹ́ òfin sí Kristi,+ kí n lè jèrè àwọn tó wà láìní òfin. 22 Nítorí àwọn aláìlera, mo di aláìlera, kí n lè jèrè àwọn aláìlera.+ Mo ti di ohun gbogbo nítorí gbogbo èèyàn, kí n lè gba àwọn kan là ní gbogbo ọ̀nà tí mo bá lè gbé e gbà. 23 Torí náà, mò ń ṣe ohun gbogbo nítorí ìhìn rere, kí n lè sọ ọ́ fún àwọn ẹlòmíì.+

24 Ṣé ẹ ò mọ̀ pé nínú gbogbo àwọn tó ń sá eré ìje, ẹnì kan ló máa gba ẹ̀bùn ni? Ẹ sáré lọ́nà tí ẹ fi lè gbà á.+ 25 Gbogbo àwọn tó ń kópa nínú ìdíje* ló máa ń kíyè sára nínú ohun gbogbo. Lóòótọ́, wọ́n ń ṣe é kí wọ́n lè gba adé tó lè bà jẹ́,+ àmọ́ àwa ń ṣe bẹ́ẹ̀ ká lè gba èyí tí kò lè bà jẹ́.+ 26 Nítorí náà, mi ò sáré láìnídìí,+ mi ò sì ju ẹ̀ṣẹ́ mi kí n lè máa gbá afẹ́fẹ́; 27 àmọ́ mò ń lu ara mi kíkankíkan,*+ mo sì ń darí rẹ̀ bí ẹrú, kó lè jẹ́ pé, lẹ́yìn tí mo bá ti wàásù fún àwọn ẹlòmíì, kí èmi fúnra mi má bàa di ẹni tí a kò tẹ́wọ́ gbà* lọ́nà kan ṣáá.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́