ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Tímótì 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Tímótì

      • Ẹ máa ṣọ́ra torí ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù (1-5)

      • Bí o ṣe lè jẹ́ òjíṣẹ́ rere fún Kristi (6-10)

        • Ìyàtọ̀ tó wà láàárín eré ìmárale àti ìfọkànsin Ọlọ́run (8)

      • Máa kíyè sí ẹ̀kọ́ rẹ (11-16)

1 Tímótì 4:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ẹ̀mí.”

  • *

    Ní Grk., “àwọn ẹ̀mí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Tẹ 2:1, 2; 2Ti 4:3, 4; 2Pe 2:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2006, ojú ìwé 23-24

    7/1/1994, ojú ìwé 9-10

    5/15/1994, ojú ìwé 15-20

    4/1/1994, ojú ìwé 9-14

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 72-73

1 Tímótì 4:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 20:29, 30; 2Ti 2:16; 2Pe 2:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 21-22

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2006, ojú ìwé 23-24

1 Tímótì 4:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 7:36; 9:5
  • +Ro 14:3
  • +Ro 14:17; 1Kọ 10:25
  • +Jẹ 9:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1996, ojú ìwé 6-7

1 Tímótì 4:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:31
  • +Iṣe 10:15

1 Tímótì 4:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 2:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 54

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2009, ojú ìwé 16-17

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    1/2005, ojú ìwé 1

1 Tímótì 4:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 6:20; Tit 1:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2020, ojú ìwé 28

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 14

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1994, ojú ìwé 29

1 Tímótì 4:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ara kíkọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 17:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 1 2020 ojú ìwé 11

    6/8/2005, ojú ìwé 11

    Ilé Ìṣọ́,

    2/1/2001, ojú ìwé 5

    1/1/1997, ojú ìwé 5

    9/1/1994, ojú ìwé 29-31

    6/15/1994, ojú ìwé 18-19

1 Tímótì 4:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 13:24
  • +Jud 25
  • +1Ti 2:3, 4

1 Tímótì 4:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 13

1 Tímótì 4:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìjẹ́mímọ́.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2022, ojú ìwé 4-9

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2018, ojú ìwé 11-12

    4/2018, ojú ìwé 13

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2015, ojú ìwé 15

    12/15/2009, ojú ìwé 12-15

    9/15/1999, ojú ìwé 31

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    9/1996, ojú ìwé 1

1 Tímótì 4:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ní gbangba.”

  • *

    Tàbí “máa fúnni níṣìírí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 4:16; 1Tẹ 5:27

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2021, ojú ìwé 24

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2019, ojú ìwé 7

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2011, ojú ìwé 18-19

    3/15/1999, ojú ìwé 20

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 26

1 Tímótì 4:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 6:5, 6; 13:2, 3; 19:6; 2Ti 1:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2015, ojú ìwé 14

    12/15/2009, ojú ìwé 11

    9/15/2008, ojú ìwé 30

    9/15/1999, ojú ìwé 29

    2/15/1998, ojú ìwé 25

    Jíjẹ́rìí Kúnnákúnná, ojú ìwé 121

1 Tímótì 4:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Máa ṣàṣàrò.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2009, ojú ìwé 11-12

    10/1/2007, ojú ìwé 21

    8/1/2001, ojú ìwé 12-17

    8/1/1992, ojú ìwé 11-12

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 74-77

    Jí!,

    3/22/1998, ojú ìwé 22

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    12/1995, ojú ìwé 2

1 Tímótì 4:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 4:2
  • +1Kọ 9:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2021, ojú ìwé 24

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 21

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2016, ojú ìwé 23

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2000, ojú ìwé 14-19

    3/15/1999, ojú ìwé 10-15

    2/15/1998, ojú ìwé 25-26

Àwọn míì

1 Tím. 4:12Tẹ 2:1, 2; 2Ti 4:3, 4; 2Pe 2:1
1 Tím. 4:2Iṣe 20:29, 30; 2Ti 2:16; 2Pe 2:3
1 Tím. 4:31Kọ 7:36; 9:5
1 Tím. 4:3Ro 14:3
1 Tím. 4:3Ro 14:17; 1Kọ 10:25
1 Tím. 4:3Jẹ 9:3
1 Tím. 4:4Jẹ 1:31
1 Tím. 4:4Iṣe 10:15
1 Tím. 4:62Ti 2:15
1 Tím. 4:71Ti 6:20; Tit 1:13, 14
1 Tím. 4:8Jo 17:3
1 Tím. 4:10Lk 13:24
1 Tím. 4:10Jud 25
1 Tím. 4:101Ti 2:3, 4
1 Tím. 4:13Kol 4:16; 1Tẹ 5:27
1 Tím. 4:14Iṣe 6:5, 6; 13:2, 3; 19:6; 2Ti 1:6
1 Tím. 4:162Ti 4:2
1 Tím. 4:161Kọ 9:22
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Tímótì 4:1-16

Ìwé Kìíní sí Tímótì

4 Àmọ́, ọ̀rọ̀ onímìísí* sọ ní kedere pé tó bá yá àwọn kan máa yẹsẹ̀ kúrò nínú ìgbàgbọ́, wọ́n á máa tẹ́tí sí àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí*+ tó ń ṣini lọ́nà àti àwọn ẹ̀kọ́ àwọn ẹ̀mí èṣù, 2 nípasẹ̀ àgàbàgebè àwọn èèyàn tó ń parọ́,+ bíi pé irin ìsàmì ti dá àpá sí ẹ̀rí ọkàn wọn. 3 Wọ́n ka ìgbéyàwó léèwọ̀,+ wọ́n pàṣẹ pé kí àwọn èèyàn yẹra fún àwọn oúnjẹ+ tí Ọlọ́run dá pé kí àwọn tó ní ìgbàgbọ́+ tí wọ́n sì mọ òtítọ́ tó péye máa jẹ,+ kí wọ́n sì máa dúpẹ́. 4 Torí gbogbo ohun tí Ọlọ́run dá ló dára,+ kò sì yẹ ká kọ ohunkóhun+ tí a bá fi ìdúpẹ́ gbà á, 5 nítorí a ti sọ ọ́ di mímọ́ nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run àti àdúrà tí a gbà sórí rẹ̀.

6 Tí o bá fún àwọn ará ní ìtọ́ni yìí, o máa jẹ́ òjíṣẹ́ rere fún Kristi Jésù, tí a fi àwọn ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ bọ́ àti ẹ̀kọ́ rere, èyí tí o ti tẹ̀ lé pẹ́kípẹ́kí.+ 7 Àmọ́, má ṣe tẹ́tí sí àwọn ìtàn èké+ tí kò buyì kúnni, irú èyí tí àwọn obìnrin tó ti darúgbó máa ń sọ. Kàkà bẹ́ẹ̀, kọ́ ara rẹ láti fi ìfọkànsin Ọlọ́run ṣe àfojúsùn rẹ. 8 Torí àǹfààní díẹ̀ wà nínú eré ìmárale,* àmọ́ ìfọkànsin Ọlọ́run ṣàǹfààní fún ohun gbogbo, ní ti pé ó ní ìlérí ìwàláàyè ní báyìí àti ìlérí ìwàláàyè ti ọjọ́ iwájú.+ 9 Ọ̀rọ̀ náà ṣeé gbára lé, ó sì yẹ ká gbà á délẹ̀délẹ̀. 10 Ìdí nìyí tí a fi ń ṣiṣẹ́ kára, tí a sì ń sa gbogbo ipá wa,+ torí a ní ìrètí nínú Ọlọ́run alààyè, tó jẹ́ Olùgbàlà+ onírúurú èèyàn,+ ní pàtàkì àwọn olóòótọ́.

11 Máa pa àṣẹ yìí fúnni, kí o sì máa fi kọ́ni. 12 Má ṣe jẹ́ kí ẹnikẹ́ni fojú ọmọdé wò ọ́ rárá. Àmọ́, kí o jẹ́ àpẹẹrẹ fún àwọn olóòótọ́ nínú ọ̀rọ̀, nínú ìwà, nínú ìfẹ́, nínú ìgbàgbọ́, nínú ìwà mímọ́.* 13 Títí màá fi dé, máa tẹra mọ́ kíkàwé fún ìjọ,*+ máa gbani níyànjú,* kí o sì máa kọ́ni. 14 Má fojú kéré ẹ̀bùn tí o ní, èyí tí a fún ọ nípasẹ̀ àsọtẹ́lẹ̀ nígbà tí ìgbìmọ̀ àwọn alàgbà gbé ọwọ́ lé ọ.+ 15 Máa ronú* lórí àwọn nǹkan yìí; jẹ́ kó gbà ọ́ lọ́kàn, kí gbogbo èèyàn lè rí i kedere pé ò ń tẹ̀ síwájú. 16 Máa kíyè sí ara rẹ àti ẹ̀kọ́ rẹ+ nígbà gbogbo. Rí i pé o ò jáwọ́ nínú ṣíṣe àwọn nǹkan yìí, torí tí o bá ń ṣe é, wàá lè gba ara rẹ àti àwọn tó ń fetí sí ọ là.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́