ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Tímótì 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Tímótì

      • Nǹkan máa le gan-an ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn (1-7)

      • Tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Pọ́ọ̀lù pẹ́kípẹ́kí (8-13)

      • “Má ṣe fi àwọn nǹkan tí o ti kọ́ sílẹ̀” (14-17)

        • Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni Ọlọ́run mí sí (16)

2 Tímótì 3:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 24:3; 1Ti 4:1; 2Pe 3:3; Jud 17, 18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 32

    Jí!,

    No. 1 2020 ojú ìwé 15

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 22

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2014, ojú ìwé 30

    6/1/2006, ojú ìwé 12

    12/1/1997, ojú ìwé 4-5

    4/15/1994, ojú ìwé 8-9, 10-11

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 105-106

2 Tímótì 3:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 22, 23-25, 27-29

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2006, ojú ìwé 5

    4/15/1994, ojú ìwé 11-12, 13-17

    Jí!,

    4/8/2000, ojú ìwé 10

    8/8/1997, ojú ìwé 6

    Ìmọ̀, ojú ìwé 103-104

2 Tímótì 3:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹni tí kì í fẹ́ ṣe àdéhùn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 29, 30-31

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2019, ojú ìwé 1

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2017, ojú ìwé 3

    Jí!,

    10/2007, ojú ìwé 9

    4/8/2000, ojú ìwé 9

    8/8/1997, ojú ìwé 6-7

    8/8/1996, ojú ìwé 17

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2011, ojú ìwé 7

    7/15/2009, ojú ìwé 12-13

    9/15/2006, ojú ìwé 5-6

    7/15/2006, ojú ìwé 27-28

    4/1/2006, ojú ìwé 8

    4/15/1994, ojú ìwé 15-18

    Ìmọ̀, ojú ìwé 104

2 Tímótì 3:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 22, 28, 30-31

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2006, ojú ìwé 6

    4/15/1994, ojú ìwé 17-18

    Jí!,

    4/8/2000, ojú ìwé 10

2 Tímótì 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 7:15, 22, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 31

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2006, ojú ìwé 6

    9/15/1997, ojú ìwé 6

    4/15/1994, ojú ìwé 18

    Ìmọ̀, ojú ìwé 104-105

2 Tímótì 3:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà agọ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 7:11, 12; 9:11

2 Tímótì 3:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 4:17; 2Ti 1:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 28-29

2 Tímótì 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 13:50
  • +Iṣe 14:1, 5, 6
  • +Iṣe 14:19
  • +2Kọ 1:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2013, ojú ìwé 28-29

2 Tímótì 3:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 16:24; Jo 15:20; Iṣe 14:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 59

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2007, ojú ìwé 14

2 Tímótì 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Tẹ 2:11; 1Ti 4:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 50

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2017, ojú ìwé 10

2 Tímótì 3:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “tí a sì ti yí ọ lérò pa dà láti gbà gbọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 1:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2017, ojú ìwé 19-20

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2016, ojú ìwé 13

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2013, ojú ìwé 12

    5/1/2007, ojú ìwé 24-26

    7/1/2006, ojú ìwé 27-28

    11/15/2000, ojú ìwé 17-18

    5/15/1998, ojú ìwé 8, 21

    3/15/1998, ojú ìwé 14-15

    11/15/1992, ojú ìwé 19-20

2 Tímótì 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 22:6
  • +Iṣe 16:1, 2
  • +Jo 5:39

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2020, ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2017, ojú ìwé 19, 20-22

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2013, ojú ìwé 16

    5/1/2007, ojú ìwé 24-25, 26-27

    7/1/2006, ojú ìwé 27-28

    4/1/2006, ojú ìwé 9

    11/15/2000, ojú ìwé 17-18

    5/15/1998, ojú ìwé 8

    4/15/1998, ojú ìwé 32

    3/15/1998, ojú ìwé 14-15

    12/1/1996, ojú ìwé 11-12

    7/15/1996, ojú ìwé 31

    5/15/1994, ojú ìwé 11-12

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 53

2 Tímótì 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “títún nǹkan ṣe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 14:26; 2Pe 1:21
  • +Ro 15:4
  • +1Kọ 10:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 1

    Jí!,

    No. 1 2021 ojú ìwé 15

    4/2010, ojú ìwé 14-15

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2016, ojú ìwé 24

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 182

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2013, ojú ìwé 12-16

    3/1/2010, ojú ìwé 3-4

    8/1/2009, ojú ìwé 13

    6/1/2008, ojú ìwé 20

    5/1/2006, ojú ìwé 24-25

    1/1/2003, ojú ìwé 30

    3/1/2002, ojú ìwé 12

    6/15/1997, ojú ìwé 3

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 6

2 Tímótì 3:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2008, ojú ìwé 20

    5/1/2006, ojú ìwé 24-25

    1/1/2000, ojú ìwé 12-13

    3/15/1994, ojú ìwé 12

Àwọn míì

2 Tím. 3:1Mt 24:3; 1Ti 4:1; 2Pe 3:3; Jud 17, 18
2 Tím. 3:5Mt 7:15, 22, 23
2 Tím. 3:9Ẹk 7:11, 12; 9:11
2 Tím. 3:101Kọ 4:17; 2Ti 1:13
2 Tím. 3:11Iṣe 13:50
2 Tím. 3:11Iṣe 14:1, 5, 6
2 Tím. 3:11Iṣe 14:19
2 Tím. 3:112Kọ 1:10
2 Tím. 3:12Mt 16:24; Jo 15:20; Iṣe 14:22
2 Tím. 3:132Tẹ 2:11; 1Ti 4:1
2 Tím. 3:142Ti 1:13
2 Tím. 3:15Owe 22:6
2 Tím. 3:15Iṣe 16:1, 2
2 Tím. 3:15Jo 5:39
2 Tím. 3:16Jo 14:26; 2Pe 1:21
2 Tím. 3:16Ro 15:4
2 Tím. 3:161Kọ 10:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Tímótì 3:1-17

Ìwé Kejì sí Tímótì

3 Àmọ́ kí o mọ èyí pé, àwọn ọjọ́ ìkẹyìn+ yóò jẹ́ àkókò tí nǹkan máa le gan-an, tó sì máa nira. 2 Torí àwọn èèyàn máa nífẹ̀ẹ́ ara wọn nìkan, wọ́n á nífẹ̀ẹ́ owó, wọ́n á jẹ́ afọ́nnu, agbéraga, asọ̀rọ̀ òdì, aṣàìgbọràn sí òbí, aláìmoore, aláìṣòótọ́, 3 ẹni tí kò ní ìfẹ́ àdámọ́ni, kìígbọ́-kìígbà,* abanijẹ́, ẹni tí kò lè kó ara rẹ̀ níjàánu, ẹni tó burú gan-an, ẹni tí kò nífẹ̀ẹ́ ohun rere, 4 ọ̀dàlẹ̀, alágídí, ajọra-ẹni-lójú, wọ́n á fẹ́ràn ìgbádùn dípò Ọlọ́run, 5 wọ́n á jọ ẹni tó ń sin Ọlọ́run tọkàntọkàn, àmọ́ ìṣe wọn ò ní fi agbára rẹ̀ hàn;+ yẹra fún irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀. 6 Lára wọn ni àwọn ọkùnrin kan ti jáde, tí wọ́n ń fi ẹ̀tàn wọnú àwọn agbo ilé, tí wọ́n sì ń tan àwọn aláìlera obìnrin tí ẹ̀ṣẹ̀ ti wọ̀ lọ́rùn, tí onírúurú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ń darí, 7 gbogbo ìgbà ni wọ́n ń kẹ́kọ̀ọ́, síbẹ̀ wọn ò ní ìmọ̀ tó péye nípa òtítọ́ rárá.

8 Bí Jánésì àti Jáńbérì ṣe ta ko Mósè, bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn yìí ṣe ń ta ko òtítọ́ ṣáá. Ìrònú irú àwọn èèyàn bẹ́ẹ̀ ti dìbàjẹ́, ìgbàgbọ́ wọn ò sì ní ìtẹ́wọ́gbà. 9 Síbẹ̀, wọn ò ní kọjá ibi tí wọ́n dé, torí ìwà òmùgọ̀* wọn máa hàn kedere sí gbogbo èèyàn, bíi tàwọn ọkùnrin méjì yẹn.+ 10 Àmọ́, o ti tẹ̀ lé ẹ̀kọ́ mi pẹ́kípẹ́kí, bí mo ṣe ń ṣe nǹkan,+ ohun tí mo ní lọ́kàn, ìgbàgbọ́ mi, sùúrù mi, ìfẹ́ mi, ìfaradà mi, 11 àwọn inúnibíni àti irú ìyà tó jẹ mí ní Áńtíókù,+ Íkóníónì+ àti Lísírà.+ Mo fara da àwọn inúnibíni yìí, Olúwa sì gbà mí nínú gbogbo wọn.+ 12 Ó dájú pé gbogbo àwọn tó bá fẹ́ fi ayé wọn sin Ọlọ́run tọkàntọkàn ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Kristi Jésù ni wọ́n máa ṣe inúnibíni sí pẹ̀lú.+ 13 Àmọ́ àwọn èèyàn burúkú àti àwọn afàwọ̀rajà á máa burú sí i, wọ́n á máa ṣi àwọn èèyàn lọ́nà, wọ́n á sì máa ṣi àwọn náà lọ́nà.+

14 Àmọ́ kí ìwọ má ṣe fi àwọn nǹkan tí o ti kọ́ sílẹ̀, tí a sì mú kí o gbà gbọ́,*+ o sì mọ ọ̀dọ̀ àwọn tí o ti kọ́ wọn 15 àti pé láti kékeré jòjòló  + lo ti mọ ìwé mímọ́,+ èyí tó lè mú kí o di ọlọ́gbọ́n kí o lè rí ìgbàlà nípasẹ̀ ìgbàgbọ́ nínú Kristi Jésù.+ 16 Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni Ọlọ́run mí sí,+ ó sì wúlò fún kíkọ́ni,+ fún bíbáni wí, fún mímú nǹkan tọ́,* fún títọ́nisọ́nà nínú òdodo,+ 17 kí èèyàn Ọlọ́run lè kúnjú ìwọ̀n dáadáa, kó sì lè gbára dì pátápátá fún gbogbo iṣẹ́ rere.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́