ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sefanáyà 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sefanáyà

      • Ẹ wá Jèhófà kí ọjọ́ ìbínú rẹ̀ tó dé (1-3)

        • Ẹ wá òdodo àti ìwà pẹ̀lẹ́ (3)

        • “Bóyá ẹ ó rí ààbò” (3)

      • Ìdájọ́ lórí àwọn orílẹ̀-èdè tó yí wọn ká (4-15)

Sefanáyà 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 1:14; 2:15, 16
  • +Ais 1:4; Jer 6:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1991, ojú ìwé 13-14

Sefanáyà 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, èèpo fúlẹ́fúlẹ́ ara ọkà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 23:26; 2Kr 36:16, 17; Jer 23:20; Ida 4:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 17-18

    2/15/2000, ojú ìwé 5

    3/1/1996, ojú ìwé 14

    5/1/1992, ojú ìwé 15-16

    5/1/1991, ojú ìwé 13-14

Sefanáyà 2:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹ̀yin onírẹ̀lẹ̀.”

  • *

    Ní Héb., “ìdájọ́ rẹ̀.”

  • *

    Tàbí “ìrẹ̀lẹ̀.”

  • *

    Tàbí “Ó lè jẹ́ pé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 55:6; Emọ 5:6
  • +Jẹ 7:13, 16; Ais 26:20; Joẹ 2:12, 14; Emọ 5:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2019, ojú ìwé 13

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2017, ojú ìwé 2

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    7/2014, ojú ìwé 3

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 11

    8/1/2005, ojú ìwé 31

    5/15/2005, ojú ìwé 30

    2/15/2001, ojú ìwé 17-20, 26-27

    2/15/2000, ojú ìwé 5

    3/1/1996, ojú ìwé 14

    8/15/1992, ojú ìwé 30

    5/1/1992, ojú ìwé 15-16

    5/1/1991, ojú ìwé 13-14

Sefanáyà 2:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọ̀sán ganrínganrín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 47:5
  • +Jer 25:17, 20; Emọ 1:6-8; Sek 9:5, 6

Sefanáyà 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 25:16, 17

Sefanáyà 2:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tọ́jú wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:11; Jer 31:7; Hag 1:12
  • +Sm 126:1; Jer 23:3; Isk 39:25; Emọ 9:14; Mik 2:12; 4:10; Sef 3:20

Sefanáyà 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 48:26, 27; Isk 25:8, 9
  • +Jer 49:1; Isk 25:3
  • +Sm 83:2, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 20

    3/1/1996, ojú ìwé 11-12, 14

Sefanáyà 2:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 25:11; Emọ 2:1, 2
  • +Jẹ 19:24, 25
  • +Emọ 1:13-15; Jud 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1996, ojú ìwé 11-12

Sefanáyà 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 16:6; Jer 48:29

Sefanáyà 2:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mú kí àyà wọn já.”

  • *

    Tàbí “rù hangogo.”

  • *

    Tàbí “jọ́sìn rẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:27; Mal 1:11

Sefanáyà 2:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 43:3; Isk 30:4, 5

Sefanáyà 2:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Na 3:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    No. 3 2017 ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2001, ojú ìwé 20-21

    3/1/1996, ojú ìwé 11-12

Sefanáyà 2:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ẹranko orílẹ̀-èdè.”

  • *

    Tàbí “wíńdò.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2007, ojú ìwé 11

Sefanáyà 2:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Na 3:1, 19

Àwọn míì

Sef. 2:1Joẹ 1:14; 2:15, 16
Sef. 2:1Ais 1:4; Jer 6:15
Sef. 2:22Ọb 23:26; 2Kr 36:16, 17; Jer 23:20; Ida 4:11
Sef. 2:3Ais 55:6; Emọ 5:6
Sef. 2:3Jẹ 7:13, 16; Ais 26:20; Joẹ 2:12, 14; Emọ 5:15
Sef. 2:4Jer 47:5
Sef. 2:4Jer 25:17, 20; Emọ 1:6-8; Sek 9:5, 6
Sef. 2:5Isk 25:16, 17
Sef. 2:7Ais 11:11; Jer 31:7; Hag 1:12
Sef. 2:7Sm 126:1; Jer 23:3; Isk 39:25; Emọ 9:14; Mik 2:12; 4:10; Sef 3:20
Sef. 2:8Jer 48:26, 27; Isk 25:8, 9
Sef. 2:8Jer 49:1; Isk 25:3
Sef. 2:8Sm 83:2, 4
Sef. 2:9Isk 25:11; Emọ 2:1, 2
Sef. 2:9Jẹ 19:24, 25
Sef. 2:9Emọ 1:13-15; Jud 7
Sef. 2:10Ais 16:6; Jer 48:29
Sef. 2:11Sm 22:27; Mal 1:11
Sef. 2:12Ais 43:3; Isk 30:4, 5
Sef. 2:13Na 3:7
Sef. 2:15Na 3:1, 19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sefanáyà 2:1-15

Sefanáyà

2 Ẹ kóra jọ, bẹ́ẹ̀ ni, ẹ kó ara yín jọ,+

Ẹ̀yin èèyàn orílẹ̀-èdè tí kò ní ìtìjú.+

 2 Kí àṣẹ náà tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́,

Kí ọjọ́ náà tó kọjá lọ bí ìyàngbò,*

Kí ìbínú tó ń jó fòfò látọ̀dọ̀ Jèhófà tó wá sórí yín,+

Kí ọjọ́ ìbínú Jèhófà tó dé bá yín,

 3 Ẹ wá Jèhófà,+ gbogbo ẹ̀yin oníwà pẹ̀lẹ́* ayé,

Tó ń pa àṣẹ òdodo* rẹ̀ mọ́.

Ẹ wá òdodo, ẹ wá ìwà pẹ̀lẹ́.*

Bóyá* ẹ ó rí ààbò ní ọjọ́ ìbínú Jèhófà.+

 4 Nítorí Gásà máa di ìlú tí a pa tì;

Áṣíkẹ́lónì á sì di ahoro.+

Áṣídódì ni wọ́n á lé jáde ní ọ̀sán gangan,*

Ẹ́kírónì ni a ó sì fà tu.+

 5 “Ẹ gbé! Ẹ̀yin tó ń gbé etí òkun, orílẹ̀-èdè àwọn Kérétì.+

Jèhófà ti bá yín wí.

Ìwọ Kénáánì, ilẹ̀ àwọn Filísínì, màá pa ọ́ run,

Tí kò fi ní sí olùgbé kan tó máa ṣẹ́ kù.

 6 Etí òkun náà á di ilẹ̀ ìjẹko,

Tó ní àwọn kànga fún àwọn olùṣọ́ àgùntàn àti àwọn ọgbà tí a fi òkúta ṣe fún àwọn àgùntàn.

 7 Á sì di agbègbè fún àwọn tó ṣẹ́ kù lára ilé Júdà;+

Ibẹ̀ ni wọ́n á ti máa jẹun.

Wọ́n á dùbúlẹ̀ sí àwọn ilé Áṣíkẹ́lónì ní ìrọ̀lẹ́.

Nítorí Jèhófà Ọlọ́run wọn máa ṣíjú àánú wò wọ́n,*

Á sì kó àwọn tó wà ní oko ẹrú lára wọn pa dà.”+

 8 “Mo ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn láti ẹnu Móábù+ àti èébú àwọn ọmọ Ámónì,+

Àwọn tó kẹ́gàn àwọn èèyàn mi, tí wọ́n sì ń halẹ̀ mọ́ wọn láti gba ilẹ̀ wọn.+

 9 Nítorí náà, bí mo ti wà láàyè,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí,

“Móábù máa dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,+

Àti àwọn ọmọ Ámónì bíi Gòmórà,+

Ibi tí èsìsì wà, tí kòtò iyọ̀ wà, tó sì ti di ahoro títí láé.+

Àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn mi á kó wọn lọ,

Àwọn tó ṣẹ́ kù nínú orílẹ̀-èdè mi á sì gba tọwọ́ wọn.

10 Èyí ni ohun tí wọ́n máa gbà nítorí ìgbéraga wọn,+

Torí pé wọ́n kẹ́gàn, wọ́n sì ń gbé ara wọn ga sí àwọn èèyàn Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.

11 Jèhófà máa dẹ́rù bà wọ́n;*

Nítorí ó máa mú kí gbogbo àwọn ọlọ́run tó wà ní ayé di asán,*

Gbogbo erékùṣù àwọn orílẹ̀-èdè á sì forí balẹ̀ fún un,*+

Láti ibi tí kálukú wọn wà.

12 Ẹ̀yin ará Etiópíà, idà mi ni yóò pa ẹ̀yin náà.+

13 Ó máa na ọwọ́ rẹ̀ sí àríwá, á sì pa Ásíríà run,

Á sọ Nínéfè di ahoro,+ á sì gbẹ bí aṣálẹ̀.

14 Àwọn agbo ẹran máa dùbúlẹ̀ sí àárín rẹ̀, gbogbo àwọn ẹranko ìgbẹ́.*

Ẹyẹ òfú àti òòrẹ̀ máa sùn mọ́jú láàárín àwọn ọpọ́n orí òpó rẹ̀.

Ohùn kan á kọrin lójú fèrèsé.*

Ibi àbáwọlé á di ahoro;

Torí pé, ó máa mú kí ilẹ̀kùn kédárì jẹ.

15 Èyí ni ìlú agbéraga tó wà ní ààbò,

Tó ń sọ nínú ọkàn rẹ̀ pé, ‘Èmi ni, kò sì sí ẹlòmíì.’

Ẹ wo bó ṣe di ohun àríbẹ̀rù,

Ibi tí àwọn ẹranko ìgbẹ́ dùbúlẹ̀ sí!

Gbogbo ẹni tó bá ń gba ọ̀dọ̀ rẹ̀ kọjá á súfèé, á sì mi orí rẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́