ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 56
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Àwọn àjèjì àti àwọn ìwẹ̀fà máa rí ìbùkún (1-8)

        • Ilé àdúrà fún gbogbo èèyàn (7)

      • Àwọn olùṣọ́ tó fọ́jú, ajá tí kò lè fọhùn (9-12)

Àìsáyà 56:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 6:8
  • +Ais 46:13; 51:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 247-248

Àìsáyà 56:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 58:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 247-249

Àìsáyà 56:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 60:10; Sek 8:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 249-252

Àìsáyà 56:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2009, ojú ìwé 26

    5/15/1992, ojú ìwé 13-14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 251-253

Àìsáyà 56:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2009, ojú ìwé 26

    5/15/1992, ojú ìwé 13-14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 251-253

Àìsáyà 56:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mal 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2010, ojú ìwé 27

    1/15/2007, ojú ìwé 10

    11/15/2000, ojú ìwé 13

    2/1/1998, ojú ìwé 22-23

    7/1/1996, ojú ìwé 20-21

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 253-257, 260

Àìsáyà 56:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 2:3; Mik 4:2; Sek 8:3
  • +1Ọb 8:29, 43; Mt 21:13; Mk 11:17; Lk 19:46

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 101-102

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 27

    2/1/1998, ojú ìwé 22-23

    7/1/1996, ojú ìwé 20-21

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 253-257, 260

Àìsáyà 56:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 30:3; Ais 27:12; Ho 1:11
  • +Ais 49:22; 60:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 257

Àìsáyà 56:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 12:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 257

Àìsáyà 56:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 6:10; 29:10
  • +Jer 6:13, 14; Isk 13:16
  • +Isk 33:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 258-260

Àìsáyà 56:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ní ọkàn tó le.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mik 3:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 258-260

Àìsáyà 56:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 5:22; 28:7; Ho 4:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 258-259

Àwọn míì

Àìsá. 56:1Mik 6:8
Àìsá. 56:1Ais 46:13; 51:5
Àìsá. 56:2Ais 58:13, 14
Àìsá. 56:3Ais 60:10; Sek 8:23
Àìsá. 56:6Mal 1:11
Àìsá. 56:7Ais 2:3; Mik 4:2; Sek 8:3
Àìsá. 56:71Ọb 8:29, 43; Mt 21:13; Mk 11:17; Lk 19:46
Àìsá. 56:8Di 30:3; Ais 27:12; Ho 1:11
Àìsá. 56:8Ais 49:22; 60:4
Àìsá. 56:9Jer 12:9
Àìsá. 56:10Ais 6:10; 29:10
Àìsá. 56:10Jer 6:13, 14; Isk 13:16
Àìsá. 56:10Isk 33:6
Àìsá. 56:11Mik 3:6
Àìsá. 56:12Ais 5:22; 28:7; Ho 4:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 56:1-12

Àìsáyà

56 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí:

“Ẹ máa ṣe ìdájọ́ òdodo,+ kí ẹ sì máa ṣe òdodo,

Torí ìgbàlà mi máa tó dé,

A sì máa ṣí òdodo mi payá.+

 2 Aláyọ̀ ni ẹni tó ń ṣe èyí

Àti ọmọ èèyàn tó rọ̀ mọ́ ọn,

Tó ń pa Sábáàtì mọ́, tí kò sì kẹ́gàn rẹ̀,+

Tí kò sì fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe ohunkóhun tó burú.

 3 Àjèjì tó bá fara mọ́ Jèhófà+ ò gbọ́dọ̀ sọ pé,

‘Ó dájú pé Jèhófà máa yà mí sọ́tọ̀ kúrò lára àwọn èèyàn rẹ̀.’

Ìwẹ̀fà ò sì gbọ́dọ̀ sọ pé, ‘Wò ó! Igi gbígbẹ ni mí.’”

4 Torí ohun tí Jèhófà sọ fún àwọn ìwẹ̀fà nìyí, àwọn tó ń pa àwọn sábáàtì mi mọ́, tí wọ́n yan ohun tí inú mi dùn sí, tí wọ́n sì rọ̀ mọ́ májẹ̀mú mi:

 5 “Màá fún wọn ní ohun ìrántí àti orúkọ ní ilé mi àti lára àwọn ògiri mi,

Ohun tó dára ju àwọn ọmọkùnrin àtàwọn ọmọbìnrin.

Màá fún wọn ní orúkọ tó máa wà títí láé,

Èyí tí kò ní pa run.

 6 Ní ti àwọn àjèjì tó fara mọ́ Jèhófà láti máa ṣe ìránṣẹ́ fún un,

Láti nífẹ̀ẹ́ orúkọ Jèhófà,+

Kí wọ́n sì di ìránṣẹ́ rẹ̀,

Gbogbo àwọn tó ń pa Sábáàtì mọ́, tí wọn ò sì kẹ́gàn rẹ̀,

Tí wọ́n ń rọ̀ mọ́ májẹ̀mú mi,

 7 Màá tún mú wọn wá sí òkè mímọ́ mi,+

Màá sì mú kí wọ́n máa yọ̀ nínú ilé àdúrà mi.

Màá tẹ́wọ́ gba odindi ẹbọ sísun wọn àtàwọn ẹbọ wọn lórí pẹpẹ mi.

Torí a ó máa pe ilé mi ní ilé àdúrà fún gbogbo èèyàn.”+

8 Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ, ẹni tó ń kó àwọn tó fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ,+ kéde pé:

“Màá kó àwọn míì jọ sọ́dọ̀ rẹ̀ yàtọ̀ sí àwọn tí a ti kó jọ tẹ́lẹ̀.”+

 9 Gbogbo ẹ̀yin ẹranko inú pápá, ẹ wá jẹun,

Gbogbo ẹ̀yin ẹran inú igbó.+

10 Afọ́jú ni àwọn olùṣọ́ rẹ̀,+ ìkankan nínú wọn ò kíyè sí i.+

Ajá tí kò lè fọhùn ni gbogbo wọn, wọn ò lè gbó.+

Wọ́n ń mí hẹlẹ, wọ́n sì dùbúlẹ̀; wọ́n fẹ́ràn oorun.

11 Ajá tó ń jẹun wọ̀mùwọ̀mù* ni wọ́n;

Wọn kì í yó.

Olùṣọ́ àgùntàn tí kò lóye ni wọ́n.+

Gbogbo wọn ti bá ọ̀nà tiwọn lọ;

Àní ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ń wá èrè tí kò tọ́ fún ara rẹ̀, ó ń sọ pé:

12 “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí n mu wáìnì díẹ̀,

Ẹ sì jẹ́ ká mu ọtí yó.+

Bí òní ṣe rí ni ọ̀la máa rí, ó tiẹ̀ máa dáa gan-an jù ú lọ!”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́