ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 22
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kíróníkà

      • Ètò tí Dáfídì ṣe sílẹ̀ fún kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-5)

      • Dáfídì sọ ohun tí Sólómọ́nì máa ṣe fún un (6-16)

      • Ó ní kí àwọn ìjòyè ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ (17-19)

1 Kíróníkà 22:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:5, 6; 2Sa 24:18; 2Kr 3:1

1 Kíróníkà 22:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 9:20, 21; 2Kr 2:17, 18
  • +1Ọb 5:15, 17; 6:7; 7:9

1 Kíróníkà 22:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Irú èyí tí àwọn káfíńtà máa ń lò.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 7:47

1 Kíróníkà 22:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 5:11
  • +1Ọb 5:6, 8
  • +2Kr 2:3

1 Kíróníkà 22:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹlẹgẹ́ sì ni.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 3:7
  • +2Kr 2:5
  • +Hag 2:3
  • +Sm 68:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2017, ojú ìwé 29

1 Kíróníkà 22:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:5, 6; 2Sa 7:2; Sm 132:3-5

1 Kíróníkà 22:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 17:4

1 Kíróníkà 22:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ìsinmi.”

  • *

    Látinú ọ̀rọ̀ Hébérù tó túmọ̀ sí “Àlàáfíà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 28:5
  • +2Sa 7:12, 13; 1Ọb 4:25; 5:4
  • +2Sa 12:24
  • +Sm 72:7

1 Kíróníkà 22:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 5:5
  • +2Sa 7:14; Heb 1:5
  • +1Kr 17:12-14; Sm 89:35, 36

1 Kíróníkà 22:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 28:20

1 Kíróníkà 22:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 1:10; Sm 72:1
  • +Di 4:6

1 Kíróníkà 22:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:37; 1Kr 28:7
  • +Di 12:1; 17:18, 19; Joṣ 1:8; 1Ọb 2:3; 1Kr 28:7; Sm 19:8, 11
  • +Joṣ 1:6, 9; 1Kr 28:20

1 Kíróníkà 22:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tálẹ́ńtì kan jẹ́ kìlógíráàmù 34.2. Wo Àfikún B14.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 29:6, 7
  • +1Kr 29:2-4

1 Kíróníkà 22:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ọb 5:17; 6:7; 7:9
  • +1Ọb 7:13, 14

1 Kíróníkà 22:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 22:3
  • +2Kr 1:1

1 Kíróníkà 22:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ọkàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 4:29; 2Kr 20:3; Da 9:3
  • +1Ọb 6:1
  • +1Ọb 8:6, 21
  • +Di 12:21; 1Ọb 8:29; 9:3

Àwọn míì

1 Kíró. 22:1Di 12:5, 6; 2Sa 24:18; 2Kr 3:1
1 Kíró. 22:21Ọb 9:20, 21; 2Kr 2:17, 18
1 Kíró. 22:21Ọb 5:15, 17; 6:7; 7:9
1 Kíró. 22:31Ọb 7:47
1 Kíró. 22:42Sa 5:11
1 Kíró. 22:41Ọb 5:6, 8
1 Kíró. 22:42Kr 2:3
1 Kíró. 22:51Ọb 3:7
1 Kíró. 22:52Kr 2:5
1 Kíró. 22:5Hag 2:3
1 Kíró. 22:5Sm 68:29
1 Kíró. 22:7Di 12:5, 6; 2Sa 7:2; Sm 132:3-5
1 Kíró. 22:81Kr 17:4
1 Kíró. 22:91Kr 28:5
1 Kíró. 22:92Sa 7:12, 13; 1Ọb 4:25; 5:4
1 Kíró. 22:92Sa 12:24
1 Kíró. 22:9Sm 72:7
1 Kíró. 22:101Ọb 5:5
1 Kíró. 22:102Sa 7:14; Heb 1:5
1 Kíró. 22:101Kr 17:12-14; Sm 89:35, 36
1 Kíró. 22:111Kr 28:20
1 Kíró. 22:122Kr 1:10; Sm 72:1
1 Kíró. 22:12Di 4:6
1 Kíró. 22:13Le 19:37; 1Kr 28:7
1 Kíró. 22:13Di 12:1; 17:18, 19; Joṣ 1:8; 1Ọb 2:3; 1Kr 28:7; Sm 19:8, 11
1 Kíró. 22:13Joṣ 1:6, 9; 1Kr 28:20
1 Kíró. 22:141Kr 29:6, 7
1 Kíró. 22:141Kr 29:2-4
1 Kíró. 22:151Ọb 5:17; 6:7; 7:9
1 Kíró. 22:151Ọb 7:13, 14
1 Kíró. 22:161Kr 22:3
1 Kíró. 22:162Kr 1:1
1 Kíró. 22:19Di 4:29; 2Kr 20:3; Da 9:3
1 Kíró. 22:191Ọb 6:1
1 Kíró. 22:191Ọb 8:6, 21
1 Kíró. 22:19Di 12:21; 1Ọb 8:29; 9:3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kíróníkà 22:1-19

Kíróníkà Kìíní

22 Nígbà náà, Dáfídì sọ pé: “Ilé Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́ nìyí, pẹpẹ ẹbọ sísun fún Ísírẹ́lì sì nìyí.”+

2 Dáfídì wá pàṣẹ pé kí wọ́n kó àwọn àjèjì+ tó wà ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì jọ, ó sì yàn wọ́n ṣe agbẹ́kùúta láti máa gé òkúta, kí wọ́n sì máa gbẹ́ òkúta tí wọ́n á fi kọ́ ilé Ọlọ́run tòótọ́.+ 3 Dáfídì tún pèsè irin tó pọ̀ gan-an láti fi ṣe ìṣó ilẹ̀kùn àwọn ẹnubodè àti àwọn ẹ̀mú,* bákan náà, ó pèsè bàbà tó pọ̀ débi pé kò ṣeé wọ̀n+ 4 àti ẹ̀là gẹdú kédárì+ tí kò níye, nítorí àwọn ọmọ Sídónì + àti àwọn ará Tírè+ kó ẹ̀là gẹdú kédárì tó pọ̀ gan-an wá fún Dáfídì. 5 Dáfídì sì sọ pé: “Sólómọ́nì ọmọ mi jẹ́ ọ̀dọ́, kò sì ní ìrírí,*+ ilé tí a máa kọ́ fún Jèhófà sì máa lẹ́wà yàtọ̀,+ kí wọ́n lè gbọ́ nípa òkìkí àti ẹwà rẹ̀+ ní gbogbo ilẹ̀.+ Nítorí náà, màá pèsè àwọn nǹkan sílẹ̀ fún un.” Dáfídì wá pèsè ọ̀pọ̀ nǹkan ìkọ́lé sílẹ̀ ṣáájú ikú rẹ̀.

6 Ó tún pe Sólómọ́nì ọmọ rẹ̀, ó sì ní kó kọ́ ilé fún Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì. 7 Dáfídì sọ fún Sólómọ́nì ọmọ rẹ̀ pé: “Ní tèmi, ìfẹ́ ọkàn mi ni láti kọ́ ilé fún orúkọ Jèhófà Ọlọ́run mi.+ 8 Àmọ́ Jèhófà bá mi sọ̀rọ̀, ó ní, ‘O ti ta ẹ̀jẹ̀ tó pọ̀ gan-an sílẹ̀, o sì ti ja àwọn ogun ńlá. O ò ní kọ́ ilé fún orúkọ mi,+ nítorí o ti ta ẹ̀jẹ̀ tó pọ̀ gan-an sílẹ̀ níwájú mi. 9 Wò ó! Wàá bí ọmọkùnrin kan+ tó máa jẹ́ ẹni àlàáfíà,* màá sì fún un ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀ tó yí i ká,+ Sólómọ́nì*+ ni orúkọ tí a máa pè é, màá sì fi àlàáfíà àti ìparọ́rọ́ jíǹkí Ísírẹ́lì ní ìgbà ayé rẹ̀.+ 10 Òun ló máa kọ́ ilé fún orúkọ mi.+ Á di ọmọ mi, màá sì di bàbá rẹ̀.+ Màá fìdí ìtẹ́ ìjọba rẹ̀ múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì títí láé.’+

11 “Wò ó, ọmọ mi, kí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ, kí o ṣe àṣeyọrí, kí o sì kọ́ ilé Jèhófà Ọlọ́run rẹ, gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ nípa rẹ.+ 12 Kìkì pé kí Jèhófà fún ọ ní làákàyè àti òye+ nígbà tó bá fún ọ ní àṣẹ lórí Ísírẹ́lì, kí o lè máa pa òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́.+ 13 Wàá sì ṣàṣeyọrí tí o bá rí i pé o tẹ̀ lé àwọn ìlànà+ àti ìdájọ́ tí Jèhófà ní kí Mósè fún Ísírẹ́lì.+ Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má bẹ̀rù, má sì jáyà.+ 14 Wò ó, mo ti sapá gan-an láti pèsè ọ̀kẹ́ márùn-ún (100,000) tálẹ́ńtì* wúrà sílẹ̀ fún ilé Jèhófà àti mílíọ̀nù kan (1,000,000) tálẹ́ńtì fàdákà pẹ̀lú bàbà àti irin+ tó pọ̀ gan-an débi pé kò ṣeé wọ̀n, mo sì ti pèsè àwọn ẹ̀là gẹdú àti òkúta+ sílẹ̀, àmọ́ wàá fi kún wọn. 15 Àwọn òṣìṣẹ́ púpọ̀ wà pẹ̀lú rẹ, ìyẹn àwọn agbẹ́kùúta, àwọn oníṣẹ́ òkúta+ àti àwọn oníṣẹ́ igi pẹ̀lú onírúurú àwọn akọ́ṣẹ́mọṣẹ́.+ 16 Wúrà, fàdákà, bàbà àti irin náà pọ̀ débi pé kò ṣeé wọ̀n.+ Dìde kí o sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà, kí Jèhófà wà pẹ̀lú rẹ.”+

17 Dáfídì wá pàṣẹ fún gbogbo àwọn ìjòyè Ísírẹ́lì pé kí wọ́n ran Sólómọ́nì ọmọ òun lọ́wọ́, ó ní: 18 “Ṣebí Jèhófà Ọlọ́run yín wà pẹ̀lú yín, ṣebí ó ti fún yín ní ìsinmi kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá tó yí yín ká? Nítorí ó fi àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà lé mi lọ́wọ́, a sì ti ṣẹ́gun ilẹ̀ náà níwájú Jèhófà àti àwọn èèyàn rẹ̀. 19 Ní báyìí, ẹ pinnu pé ẹ máa fi gbogbo ọkàn yín àti gbogbo ara* yín wá Jèhófà Ọlọ́run yín,+ kí ẹ sì bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ibi mímọ́ Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́,+ láti gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà àti àwọn nǹkan èlò mímọ́ ti Ọlọ́run tòótọ́+ wá sínú ilé tí a kọ́ fún orúkọ Jèhófà.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́