ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 137
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sáàmù

      • Létí àwọn odò Bábílónì

        • Wọn ò kọ orin Síónì (3, 4)

        • Bábílónì máa di ahoro (8)

Sáàmù 137:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:13; Isk 3:15; Da 10:4
  • +Da 9:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 139-140, 145-146

Sáàmù 137:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ń tọ́ka sí Bábílónì.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 24:8

Sáàmù 137:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 123:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 96

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 139-140

Sáàmù 137:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 139-140

Sáàmù 137:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Kí ọwọ́ ọ̀tún mi rọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 2:3; Sm 84:2; 102:13, 14; Ais 62:1; Jer 51:50

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 141-142, 147

Sáàmù 137:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 122:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/1998, ojú ìwé 13-14

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 141-142, 147

Sáàmù 137:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 49:7; Ida 4:22; Isk 25:12; Ọbd 10-13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 124, 147-148

Sáàmù 137:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 47:1; Jer 25:12; 50:2
  • +Jer 50:29; Ifi 18:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 148-151

Sáàmù 137:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 13:1, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 148-151

Àwọn míì

Sm 137:1Jer 51:13; Isk 3:15; Da 10:4
Sm 137:1Da 9:2, 3
Sm 137:2Ais 24:8
Sm 137:3Sm 123:4
Sm 137:5Ne 2:3; Sm 84:2; 102:13, 14; Ais 62:1; Jer 51:50
Sm 137:6Sm 122:1
Sm 137:7Jer 49:7; Ida 4:22; Isk 25:12; Ọbd 10-13
Sm 137:8Ais 47:1; Jer 25:12; 50:2
Sm 137:8Jer 50:29; Ifi 18:6
Sm 137:9Ais 13:1, 16
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sáàmù 137:1-9

Sáàmù

137 Létí àwọn odò Bábílónì,+ ibẹ̀ la jókòó sí.

A sunkún nígbà tí a rántí Síónì.+

2 Orí àwọn igi pọ́pílà tó wà láàárín rẹ̀*

Ni a gbé àwọn háàpù wa kọ́.+

3 Ibẹ̀ ni àwọn tó mú wa lẹ́rú ti ní ká kọrin,+

Àwọn tó ń fi wá ṣẹ̀sín fẹ́ ká dá àwọn lára yá, wọ́n ní:

“Ẹ kọ ọ̀kan lára àwọn orin Síónì fún wa.”

4 Báwo la ó ṣe kọ orin Jèhófà

Ní ilẹ̀ àjèjì?

5 Tí mo bá gbàgbé rẹ, ìwọ Jerúsálẹ́mù,

Kí ọwọ́ ọ̀tún mi gbàgbé ohun tó mọ̀ ọ́n ṣe.*+

6 Kí ahọ́n mi lẹ̀ mọ́ òkè ẹnu mi

Tí mi ò bá rántí rẹ,

Tí mi ò bá gbé Jerúsálẹ́mù ga kọjá

Olórí ohun tó ń fún mi láyọ̀.+

7 Jèhófà, jọ̀wọ́ rántí

Ohun tí àwọn ọmọ Édómù sọ lọ́jọ́ tí Jerúsálẹ́mù ṣubú, wọ́n ní:

“Ẹ wó o palẹ̀! Ẹ wó o palẹ̀ dé ìpìlẹ̀ rẹ̀!”+

8 Ìwọ ọmọbìnrin Bábílónì, tí kò ní pẹ́ di ahoro,+

Aláyọ̀ ni ẹni tó máa san ọ́ lẹ́san

Lórí ohun tí o ṣe sí wa.+

9 Aláyọ̀ ni ẹni tó máa gba àwọn ọmọ rẹ lọ́wọ́ rẹ,

Tí á sì là wọ́n mọ́ àpáta.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́