ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 46
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Àwọn òrìṣà Bábílónì àti Ọlọ́run Ísírẹ́lì (1-13)

        • Jèhófà ń sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú (10)

        • Ẹyẹ aṣọdẹ láti ìlà oòrùn (11)

Àìsáyà 46:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:2; 51:44
  • +Ais 45:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 93-95

Àìsáyà 46:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àwọn òrìṣà tí wọ́n kó sẹ́yìn àwọn ẹranko.

  • *

    Tàbí “Ọkàn wọn.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 95-96

Àìsáyà 46:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 1:9
  • +Ẹk 19:4; Di 1:31; Ais 44:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 96-97

Àìsáyà 46:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:4
  • +Ais 43:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 97

Àìsáyà 46:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 15:11
  • +Iṣe 17:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 97-99

Àìsáyà 46:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “forí balẹ̀ fún un.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:19; Jer 10:8, 9
  • +Ais 44:16, 17; Da 3:1, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 99

Àìsáyà 46:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 10:5
  • +1Sa 5:3
  • +1Ọb 18:26; Ais 37:37, 38; Jon 1:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 99-100

Àìsáyà 46:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 100-102

Àìsáyà 46:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àkọ́kọ́.”

  • *

    Tàbí “Olú Ọ̀run.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 33:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 100

Àìsáyà 46:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ohun tí mo ní lọ́kàn; Ìmọ̀ràn mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:9; 45:21
  • +Sm 33:11
  • +Sm 135:6; Ais 55:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 3

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2011, ojú ìwé 14

    6/1/2006, ojú ìwé 21-22

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 102

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 19-20

Àìsáyà 46:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìlà oòrùn.”

  • *

    Tàbí “ohun tí mo ní lọ́kàn; ìmọ̀ràn mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:2; 45:1
  • +Ẹsr 1:1, 2; Ais 44:28; 48:14
  • +Nọ 23:19; Job 23:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 102-103

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/1999, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 149

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 19-20

Àìsáyà 46:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “ọlọ́kàn tó yi.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 103

Àìsáyà 46:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 12:2; 51:5; 62:11
  • +Ais 44:23; 60:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 103-104

Àwọn míì

Àìsá. 46:1Jer 50:2; 51:44
Àìsá. 46:1Ais 45:20
Àìsá. 46:3Ais 1:9
Àìsá. 46:3Ẹk 19:4; Di 1:31; Ais 44:2
Àìsá. 46:4Ais 41:4
Àìsá. 46:4Ais 43:13
Àìsá. 46:5Ẹk 15:11
Àìsá. 46:5Iṣe 17:29
Àìsá. 46:6Ais 40:19; Jer 10:8, 9
Àìsá. 46:6Ais 44:16, 17; Da 3:1, 5
Àìsá. 46:7Jer 10:5
Àìsá. 46:71Sa 5:3
Àìsá. 46:71Ọb 18:26; Ais 37:37, 38; Jon 1:5
Àìsá. 46:9Di 33:26
Àìsá. 46:10Ais 42:9; 45:21
Àìsá. 46:10Sm 33:11
Àìsá. 46:10Sm 135:6; Ais 55:10, 11
Àìsá. 46:11Ais 41:2; 45:1
Àìsá. 46:11Ẹsr 1:1, 2; Ais 44:28; 48:14
Àìsá. 46:11Nọ 23:19; Job 23:13
Àìsá. 46:13Ais 12:2; 51:5; 62:11
Àìsá. 46:13Ais 44:23; 60:21
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 46:1-13

Àìsáyà

46 Bélì bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀,+ Nébò tẹ̀ ba síwájú.

Wọ́n kó àwọn òrìṣà wọn sẹ́yìn àwọn ẹranko, sẹ́yìn àwọn ẹran akẹ́rù,+

Bí ẹrù tó ń ni àwọn ẹranko tó ti rẹ̀ lára.

 2 Wọ́n jọ tẹ̀ ba, wọ́n sì jọ bẹ̀rẹ̀ mọ́lẹ̀;

Wọn ò lè gba àwọn ẹrù* náà sílẹ̀,

Àwọn fúnra wọn* sì lọ sí ìgbèkùn.

 3 “Fetí sí mi, ìwọ ilé Jékọ́bù àti gbogbo ẹ̀yin tó ṣẹ́ kù ní ilé Ísírẹ́lì,+

Ẹ̀yin tí mò ń tì lẹ́yìn látìgbà tí a ti bí yín, tí mo sì gbé látinú oyún.+

 4 Títí o fi máa dàgbà, mi ò ní yí pa dà;+

Títí irun rẹ fi máa funfun, mi ò ní yéé gbé ọ.

Bí mo ti ń ṣe, màá gbé ọ, màá rù ọ́, màá sì gbà ọ́ sílẹ̀.+

 5 Ta lẹ lè fi mí wé, tí ẹ lè mú bá mi dọ́gba tàbí tí ẹ lè fi díwọ̀n mi,+

Tí a máa wá rí bákan náà?+

 6 Àwọn kan wà tó ń kó wúrà jáde yàlàyòlò látinú àpò wọn;

Wọ́n ń wọn fàdákà lórí òṣùwọ̀n.

Wọ́n gba oníṣẹ́ irin síṣẹ́, ó sì fi ṣe ọlọ́run.+

Wọ́n wá wólẹ̀, àní, wọ́n jọ́sìn rẹ̀.*+

 7 Wọ́n gbé e sí èjìká wọn,+

Wọ́n gbé e, wọ́n sì fi sí àyè rẹ̀, ṣe ló kàn dúró síbẹ̀.

Kì í kúrò ní àyè rẹ̀.+

Wọ́n ké sí i, àmọ́ kò dáhùn;

Kò lè gba ẹnikẹ́ni nínú wàhálà.+

 8 Ẹ rántí èyí, kí ẹ sì mọ́kàn le.

Ẹ fi sọ́kàn, ẹ̀yin ẹlẹ́ṣẹ̀.

 9 Ẹ rántí àwọn nǹkan àtijọ́* tó ti wà tipẹ́,

Pé èmi ni Ọlọ́run,* kò sí ẹlòmíì,

Èmi ni Ọlọ́run, kò sí ẹni tó dà bí èmi.+

10 Láti ìbẹ̀rẹ̀, mò ń sọ ohun tó máa ṣẹlẹ̀,

Tipẹ́tipẹ́ ni mo sì ti ń sọ àwọn ohun tí kò tíì ṣẹlẹ̀.+

Mo sọ pé, ‘Ìpinnu mi* máa dúró,+

Màá sì ṣe ohunkóhun tó bá wù mí.’+

11 Màá pe ẹyẹ aṣọdẹ wá láti ibi tí oòrùn ti ń yọ,*+

Ọkùnrin tó máa ṣe ohun tí mo pinnu*+ máa wá láti ilẹ̀ tó jìn.

Mo ti sọ̀rọ̀, màá sì mú kó ṣẹ.

Mo ti ní in lọ́kàn, màá sì ṣe é.+

12 Ẹ fetí sí mi, ẹ̀yin ọlọ́kàn líle,*

Ẹ̀yin tí ẹ jìnnà réré sí òdodo.

13 Mo ti mú òdodo mi sún mọ́ tòsí;

Kò jìnnà réré,

Ìgbàlà mi ò sì ní falẹ̀.+

Màá mú kí wọ́n rí ìgbàlà ní Síónì, ẹwà mi sì máa wà ní Ísírẹ́lì.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́