ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kíróníkà 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kíróníkà

      • Àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà tó ṣẹ́ kù (1-23)

        • Jábésì àti àdúrà rẹ̀ (9, 10)

      • Àwọn àtọmọdọ́mọ Síméónì (24-43)

1 Kíróníkà 4:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 38:29; Nọ 26:20; Rut 4:18; Mt 1:3
  • +Jẹ 46:12; 1Kr 2:5
  • +Ẹk 17:12; 24:14; 1Kr 2:19
  • +1Kr 2:50

1 Kíróníkà 4:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 2:53

1 Kíróníkà 4:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 11:5, 6

1 Kíróníkà 4:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní àwọn ibì kan nínú orí yìí, “bàbá” lè túmọ̀ sí ẹni tí ó tẹ ìlú kan dó.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 2:19
  • +Mik 5:2

1 Kíróníkà 4:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 2:24
  • +2Kr 11:5, 6

1 Kíróníkà 4:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Orúkọ Jábésì ṣeé ṣe kó jẹ mọ́ ọ̀rọ̀ Hébérù tó túmọ̀ sí “ìrora.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2010, ojú ìwé 23

1 Kíróníkà 4:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2010, ojú ìwé 23

    10/1/2005, ojú ìwé 9

1 Kíróníkà 4:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:16, 17; Ond 3:9, 11

1 Kíróníkà 4:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Àfonífojì Àwọn Oníṣẹ́ Ọnà.”

1 Kíróníkà 4:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 32:11, 12; Joṣ 15:13

1 Kíróníkà 4:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ Bitáyà ní ẹsẹ 18 ló ń tọ́ka sí.

1 Kíróníkà 4:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bàbá.”

1 Kíróníkà 4:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 38:2, 5; Nọ 26:20

1 Kíróníkà 4:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn ọ̀rọ̀ yìí wá látinú àṣà àtijọ́.”

1 Kíróníkà 4:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 46:10
  • +Nọ 26:12, 13

1 Kíróníkà 4:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ọ̀rọ̀ yìí ní Hébérù lè túmọ̀ sí ọmọ, ọmọ ọmọ tàbí àtọmọdọ́mọ.

1 Kíróníkà 4:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 26:22

1 Kíróníkà 4:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:1, 2
  • +Joṣ 15:21, 26
  • +Joṣ 15:21, 28; 19:1, 3; Ne 11:25-27

1 Kíróníkà 4:29

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 15:21, 29

1 Kíróníkà 4:30

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:1, 4
  • +Ond 1:17
  • +Joṣ 15:20, 31; 19:1, 5; 1Sa 27:5, 6

1 Kíróníkà 4:31

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:1, 5

1 Kíróníkà 4:32

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 19:1, 7

1 Kíróníkà 4:40

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 10:6, 20

1 Kíróníkà 4:41

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 29:1

1 Kíróníkà 4:42

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 36:8

1 Kíróníkà 4:43

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 17:14, 16; 1Sa 15:7

Àwọn míì

1 Kíró. 4:1Jẹ 38:29; Nọ 26:20; Rut 4:18; Mt 1:3
1 Kíró. 4:1Jẹ 46:12; 1Kr 2:5
1 Kíró. 4:1Ẹk 17:12; 24:14; 1Kr 2:19
1 Kíró. 4:11Kr 2:50
1 Kíró. 4:21Kr 2:53
1 Kíró. 4:32Kr 11:5, 6
1 Kíró. 4:41Kr 2:19
1 Kíró. 4:4Mik 5:2
1 Kíró. 4:51Kr 2:24
1 Kíró. 4:52Kr 11:5, 6
1 Kíró. 4:13Joṣ 15:16, 17; Ond 3:9, 11
1 Kíró. 4:15Nọ 32:11, 12; Joṣ 15:13
1 Kíró. 4:21Jẹ 38:2, 5; Nọ 26:20
1 Kíró. 4:24Jẹ 46:10
1 Kíró. 4:24Nọ 26:12, 13
1 Kíró. 4:27Nọ 26:22
1 Kíró. 4:28Joṣ 19:1, 2
1 Kíró. 4:28Joṣ 15:21, 26
1 Kíró. 4:28Joṣ 15:21, 28; 19:1, 3; Ne 11:25-27
1 Kíró. 4:29Joṣ 15:21, 29
1 Kíró. 4:30Joṣ 19:1, 4
1 Kíró. 4:30Ond 1:17
1 Kíró. 4:30Joṣ 15:20, 31; 19:1, 5; 1Sa 27:5, 6
1 Kíró. 4:31Joṣ 19:1, 5
1 Kíró. 4:32Joṣ 19:1, 7
1 Kíró. 4:40Jẹ 10:6, 20
1 Kíró. 4:412Kr 29:1
1 Kíró. 4:42Jẹ 36:8
1 Kíró. 4:43Ẹk 17:14, 16; 1Sa 15:7
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
  • 30
  • 31
  • 32
  • 33
  • 34
  • 35
  • 36
  • 37
  • 38
  • 39
  • 40
  • 41
  • 42
  • 43
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kíróníkà 4:1-43

Kíróníkà Kìíní

4 Àwọn ọmọ Júdà ni Pérésì,+ Hésírónì,+ Kámì, Húrì+ àti Ṣóbálì.+ 2 Reáyà ọmọ Ṣóbálì bí Jáhátì; Jáhátì bí Áhúmáì àti Láhádì. Àwọn ni ìdílé àwọn Sórátì.+ 3 Àwọn ọmọ bàbá Étámì  + nìyí: Jésírẹ́lì, Íṣímà àti Ídíbáṣì, (orúkọ arábìnrin wọn sì ni Haselelipónì), 4 Pénúélì ni bàbá* Gédórì, Ésérì sì ni bàbá Húṣà. Àwọn ni àwọn ọmọ Húrì,+ àkọ́bí Éfúrátà bàbá Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.+ 5 Áṣíhúrì+ bàbá Tékóà+ ní ìyàwó méjì, Hélà àti Náárà. 6 Náárà bí Áhúsámù, Héfà, Téménì àti Hááháṣítárì fún un. Àwọn ni àwọn ọmọ Náárà. 7 Àwọn ọmọ Hélà sì ni Sérétì, Ísárì àti Étínánì. 8 Kósì bí Ánúbù, Sóbébà àti àwọn ìdílé Áhárélì ọmọ Hárúmù.

9 Jábésì gbayì ju àwọn arákùnrin rẹ̀ lọ; ìyá rẹ̀ sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jábésì,* ó sọ pé: “Mo bí i nínú ìrora.” 10 Jábésì ké pe Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ó ní: “Jọ̀wọ́ bù kún mi, kí o jẹ́ kí ìpínlẹ̀ mi fẹ̀ sí i, kí ọwọ́ rẹ wà pẹ̀lú mi, kí o sì pa mí mọ́ nínú àjálù, kí ó má bàa ṣe mí léṣe!” Torí náà, Ọlọ́run ṣe ohun tí ó béèrè.

11 Kélúbù arákùnrin Ṣúhà bí Méhírì tó jẹ́ bàbá Éṣítónì. 12 Éṣítónì bí Bẹti-ráfà, Páséà àti Téhínà bàbá Iri-náháṣì. Àwọn ló ń gbé ní Rékà. 13 Àwọn ọmọ Kénásì ni Ótíníẹ́lì+ àti Seráyà, ọmọ* Ótíníẹ́lì sì ni Hátátì. 14 Mèónótáì bí Ọ́fírà. Seráyà bí Jóábù bàbá Ge-háráṣímù,* wọ́n ń pè wọ́n bẹ́ẹ̀ torí pé oníṣẹ́ ọnà ni wọ́n.

15 Àwọn ọmọ Kélẹ́bù+ ọmọ Jéfúnè ni Írù, Élà àti Náámù; ọmọ* Élà sì ni Kénásì. 16 Àwọn ọmọ Jéhálélélì ni Sífù, Sífà, Tíríà àti Ásárélì. 17 Àwọn ọmọ Ésírà ni Jétà, Mérédì, Éférì àti Jálónì; ó* lóyún, ó sì bí Míríámù, Ṣámáì àti Íṣíbà bàbá Éṣítémóà. 18 (Mérédì ní ìyàwó Júù kan, òun ló bí Jérédì bàbá Gédórì, Hébà bàbá Sókò àti Jékútíélì bàbá Sánóà.) Àwọn ni ọmọ Bitáyà ọmọbìnrin Fáráò, tí Mérédì fẹ́.

19 Àwọn ọmọ ìyàwó Hodáyà, arábìnrin Náhámù ni olùtẹ̀dó* Kéílà ti àwọn ọmọ Gámì àti Éṣítémóà ti àwọn ará Máákátì. 20 Àwọn ọmọ Ṣímónì ni Ámínónì, Rínà, Bẹni-hánánì àti Tílónì. Àwọn ọmọ Íṣì sì ni Sóhétì àti Bẹni-sóhétì.

21 Àwọn ọmọ Ṣélà+ ọmọ Júdà ni Éérì bàbá Lékà, Láádà bàbá Máréṣà àti àwọn ìdílé àwọn tó ń hun aṣọ àtàtà ti ilé Áṣíbéà, 22 Jókímù, àwọn ọkùnrin Kósébà, Jóáṣì àti Sáráfì, àwọn ni wọ́n fi àwọn obìnrin ará Móábù ṣe aya àti Jaṣubi-léhémù. Àkọsílẹ̀ wọ̀nyí jẹ́ ti àtijọ́.* 23 Àwọn ni amọ̀kòkò tó ń gbé Nétáímù àti Gédérà. Ibẹ̀ ni wọ́n ń gbé tí wọ́n ti ń ṣiṣẹ́ fún ọba.

24 Àwọn ọmọ Síméónì+ ni Némúẹ́lì, Jámínì, Járíbù, Síírà àti Ṣéọ́lù.+ 25 Ọmọ rẹ̀ ni Ṣálúmù, ọmọ rẹ̀ ni Míbúsámù, ọmọ rẹ̀ sì ni Míṣímà. 26 Àwọn ọmọ Míṣímà ni Hámúélì, ọmọ* rẹ̀ ni Sákúrì, ọmọ rẹ̀ ni Ṣíméì. 27 Ṣíméì sì ní ọmọkùnrin mẹ́rìndínlógún (16) àti ọmọbìnrin mẹ́fà; ṣùgbọ́n àwọn arákùnrin rẹ̀ kò ní ọmọ púpọ̀, kò sì sí ìkankan nínú ìdílé wọn tó ní ọmọ tó pọ̀ tó ti àwọn ọmọ Júdà.+ 28 Wọ́n ń gbé ní Bíá-ṣébà,+ Móládà,+ Hasari-ṣúálì,+ 29 Bílíhà, Ésémù,+ Tóládì, 30 Bẹ́túẹ́lì,+ Hóómà,+ Síkílágì,+ 31 Bẹti-mákábótì, Hasari-súsímù,+ Bẹti-bírì àti Ṣááráímù. Ìwọ̀nyí ni ìlú wọn títí di ìgbà tí Dáfídì jọba.

32 Ibi tí wọ́n tẹ̀ dó sí ni Étámì, Áyínì, Rímónì, Tókénì àti Áṣánì,+ ìlú márùn-ún, 33 pẹ̀lú àwọn ibi tí wọ́n gbé tó wà yí ká gbogbo àwọn ìlú yìí títí dé Báálì. Ìwọ̀nyí ni orúkọ àwọn tó wà nínú àkọsílẹ̀ ìdílé wọn àti àwọn ibi tí wọ́n gbé. 34 Méṣóbábù, Jámílẹ́kì, Jóṣà ọmọ Amasááyà, 35 Jóẹ́lì, Jéhù ọmọ Joṣibáyà ọmọ Seráyà ọmọ Ásíélì, 36 Élíóénáì, Jáákóbà, Jeṣoháyà, Ásáyà, Ádíélì, Jésímíélì, Bẹnáyà 37 àti Sísà ọmọ Ṣífì ọmọ Álónì ọmọ Jedáyà ọmọ Ṣímúrì ọmọ Ṣemáyà; 38 àwọn tí a dárúkọ wọn yìí jẹ́ ìjòyè nínú ìdílé wọn, àwọn tó wà nínú agbo ilé àwọn baba ńlá wọn sì ń pọ̀ sí i. 39 Wọ́n lọ sí àbáwọlé Gédórì, sápá ìlà oòrùn àfonífojì, láti wá ibi ìjẹko fún àwọn agbo ẹran wọn. 40 Níkẹyìn, wọ́n rí àwọn ibi ìjẹko tó lọ́ràá tó sì dára, ilẹ̀ náà fẹ̀, ó pa rọ́rọ́, kò sì sí ìyọlẹ́nu níbẹ̀. Àwọn ọmọ Hámù+ ló ń gbé ibẹ̀ tẹ́lẹ̀. 41 Àwọn tí a kọ orúkọ wọn sílẹ̀ yìí jáde wá nígbà ayé Hẹsikáyà+ ọba Júdà, wọ́n sì wó àgọ́ àwọn ọmọ Hámù àti ti Méúnímù tó wà níbẹ̀ lulẹ̀. Wọ́n pa wọ́n run títí di òní yìí; wọ́n sì ń gbé ní àyè wọn, torí pé àwọn ibi tí agbo ẹran wọn ti lè máa jẹko wà níbẹ̀.

42 Àwọn kan lára àwọn ọmọ Síméónì, àwọn ọgọ́rùn-ún márùn-ún (500), lọ sí Òkè Séírì+ pẹ̀lú Pẹlatáyà, Nearáyà, Refáyà àti Úsíélì, àwọn ọmọ Íṣì tí wọ́n ṣáájú wọn. 43 Wọ́n pa àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn Ámálékì+ tó yè bọ́, wọ́n sì ń gbé ibẹ̀ títí di òní yìí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́