ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Ẹjọ́ ìṣekúṣe tó wáyé (1-5)

      • Ìwúkàrà díẹ̀ ló ń mú gbogbo ìṣùpọ̀ wú (6-8)

      • Ẹ mú ẹni burúkú náà kúrò (9-13)

1 Kọ́ríńtì 5:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Lédè Gíríìkì, por·neiʹa. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Lédè Gíríìkì, por·neiʹa. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí “ń gbé pẹ̀lú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 5:3
  • +Le 18:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/1997, ojú ìwé 28

1 Kọ́ríńtì 5:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 7:9
  • +1Kọ 5:13; 2Jo 10

1 Kọ́ríńtì 5:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 1:20
  • +1Kọ 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2012, ojú ìwé 21

    7/15/2008, ojú ìwé 26-27

    11/15/2006, ojú ìwé 27

1 Kọ́ríńtì 5:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 15:33; Ga 5:9; 2Ti 2:16, 17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 57

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2019, ojú ìwé 5

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/15/1993, ojú ìwé 5

1 Kọ́ríńtì 5:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:29
  • +1Pe 1:19, 20; Ifi 5:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    4/2018, ojú ìwé 2

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2013, ojú ìwé 19

    3/15/1994, ojú ìwé 4

    3/15/1993, ojú ìwé 5

1 Kọ́ríńtì 5:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 13:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/15/1993, ojú ìwé 5

1 Kọ́ríńtì 5:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “dídarapọ̀.”

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ìṣekúṣe.”

1 Kọ́ríńtì 5:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ìṣekúṣe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 2:17
  • +Jo 17:15

1 Kọ́ríńtì 5:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “dídarapọ̀.”

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ìṣekúṣe.”

  • *

    Tàbí “ẹlẹ́rẹ̀kẹ́ èébú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 16:25, 26; Ro 16:17; 2Jo 10
  • +Ef 5:5
  • +Di 21:20, 21; 1Pe 4:3
  • +1Kọ 6:9, 10; Ga 5:19-21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 58

    Jí!,

    9/8/1996, ojú ìwé 26-27

    Ayọ, ojú ìwé 172-174

1 Kọ́ríńtì 5:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

    Ayọ, ojú ìwé 172-174

1 Kọ́ríńtì 5:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 12:14
  • +Jẹ 3:23, 24; Di 17:7; Tit 3:10; 2Jo 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2021,

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2015, ojú ìwé 30

    5/15/1995, ojú ìwé 13

    Ayọ, ojú ìwé 172-174

Àwọn míì

1 Kọ́r. 5:1Ef 5:3
1 Kọ́r. 5:1Le 18:8
1 Kọ́r. 5:21Kọ 5:13; 2Jo 10
1 Kọ́r. 5:22Kọ 7:9
1 Kọ́r. 5:51Ti 1:20
1 Kọ́r. 5:51Kọ 1:8
1 Kọ́r. 5:61Kọ 15:33; Ga 5:9; 2Ti 2:16, 17
1 Kọ́r. 5:7Jo 1:29
1 Kọ́r. 5:71Pe 1:19, 20; Ifi 5:12
1 Kọ́r. 5:8Ẹk 13:7
1 Kọ́r. 5:101Jo 2:17
1 Kọ́r. 5:10Jo 17:15
1 Kọ́r. 5:11Nọ 16:25, 26; Ro 16:17; 2Jo 10
1 Kọ́r. 5:11Ef 5:5
1 Kọ́r. 5:11Di 21:20, 21; 1Pe 4:3
1 Kọ́r. 5:111Kọ 6:9, 10; Ga 5:19-21
1 Kọ́r. 5:13Onw 12:14
1 Kọ́r. 5:13Jẹ 3:23, 24; Di 17:7; Tit 3:10; 2Jo 10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 5:1-13

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

5 Ní tòótọ́, wọ́n ròyìn ìṣekúṣe*+ tó ṣẹlẹ̀ láàárín yín, irú ìṣekúṣe* bẹ́ẹ̀ kò tiẹ̀ sí láàárín àwọn orílẹ̀-èdè, pé ọkùnrin kan ń fẹ́* ìyàwó bàbá rẹ̀.+ 2 Ṣé ẹ wá ń fìyẹn yangàn ni? Ṣé kì í ṣe pé ó yẹ kí ẹ máa ṣọ̀fọ̀+ kí a lè mú ọkùnrin tó ṣe nǹkan yìí kúrò láàárín yín?+ 3 Bí mi ò tiẹ̀ sí lọ́dọ̀ yín nípa tara, mo wà lọ́dọ̀ yín nípa tẹ̀mí, mo sì ti ṣèdájọ́ ọkùnrin tó ṣe nǹkan yìí, bíi pé èmi fúnra mi wà lọ́dọ̀ yín. 4 Nígbà tí ẹ bá pé jọ ní orúkọ Olúwa wa Jésù, tí ẹ sì mọ̀ pé mo wà pẹ̀lú yín nípa tẹ̀mí nínú agbára Olúwa wa Jésù, 5 kí ẹ fi irú ẹni bẹ́ẹ̀ lé Sátánì lọ́wọ́+ kí agbára ẹ̀ṣẹ̀ náà lè pa run, kí ipò tẹ̀mí ìjọ lè wà láìyingin ní ọjọ́ Olúwa.+

6 Bí ẹ ṣe ń fọ́nnu yìí kò dáa. Ṣé ẹ kò mọ̀ pé ìwúkàrà díẹ̀ ló ń mú gbogbo ìṣùpọ̀ wú ni?+ 7 Ẹ mú ìwúkàrà àtijọ́ kúrò, kí ẹ lè di ìṣùpọ̀ tuntun, tí kò bá ti sí amóhunwú nínú yín. Torí, ní tòótọ́, a ti fi Kristi ọ̀dọ́ àgùntàn Ìrékọjá wa+ rúbọ.+ 8 Nítorí náà, ẹ jẹ́ ká ṣe àjọyọ̀,+ kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà àtijọ́, bẹ́ẹ̀ ni kì í ṣe pẹ̀lú ìwúkàrà ìwà ìbàjẹ́ àti ìwà burúkú, àmọ́ ká ṣe é pẹ̀lú búrẹ́dì aláìwú ti òótọ́ inú àti ti òtítọ́.

9 Nínú lẹ́tà tí mo kọ sí yín, mo ní kí ẹ jáwọ́ nínú kíkẹ́gbẹ́* pẹ̀lú àwọn oníṣekúṣe,* 10 àmọ́ kì í ṣe gbogbo àwọn oníṣekúṣe* ayé yìí+ tàbí àwọn olójúkòkòrò tàbí àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà tàbí àwọn abọ̀rìṣà ni mò ń sọ. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, á di pé kí ẹ kúrò nínú ayé.+ 11 Ṣùgbọ́n ní báyìí mò ń kọ̀wé sí yín pé kí ẹ jáwọ́ nínú kíkẹ́gbẹ́*+ pẹ̀lú ẹnikẹ́ni tí a pè ní arákùnrin, àmọ́ tó jẹ́ oníṣekúṣe* tàbí olójúkòkòrò+ tàbí abọ̀rìṣà tàbí pẹ̀gànpẹ̀gàn* tàbí ọ̀mùtípara+ tàbí alọ́nilọ́wọ́gbà,+ kí ẹ má tiẹ̀ bá irú ẹni bẹ́ẹ̀ jẹun. 12 Torí kí ló kàn mí pẹ̀lú ṣíṣèdájọ́ àwọn tó wà lóde? Ṣebí àwọn tó wà nínú ìjọ lẹ̀ ń dá lẹ́jọ́, 13 nígbà tí Ọlọ́run ń dá àwọn tó wà lóde lẹ́jọ́?+ “Ẹ mú ẹni burúkú náà kúrò láàárín yín.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́