ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Ọ̀rọ̀ nípa oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà (1-13)

        • Ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà (5, 6)

1 Kọ́ríńtì 8:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 15:20, 29
  • +Ro 14:14; 1Kọ 8:10
  • +1Kọ 8:13; 13:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2018, ojú ìwé 12-16

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2017, ojú ìwé 29

    Jí!,

    1/2009, ojú ìwé 8

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2001, ojú ìwé 9

    11/15/1992, ojú ìwé 21-22

1 Kọ́ríńtì 8:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2019, ojú ìwé 12

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2018, ojú ìwé 8

1 Kọ́ríńtì 8:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:21; 2Ọb 19:17, 18; Jer 16:20
  • +Di 6:4; 32:39

1 Kọ́ríńtì 8:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 82:1, 6; Jo 10:34, 35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1992, ojú ìwé 3-4

1 Kọ́ríńtì 8:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 2:5
  • +Mal 2:10; Mt 23:9
  • +Iṣe 17:28; Ro 11:36
  • +Jo 1:1, 3; Kol 1:15, 16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Mẹtalọkan, ojú ìwé 14

1 Kọ́ríńtì 8:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “sọ ẹ̀rí ọkàn wọn tí kò lágbára di ẹlẹ́gbin.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:14
  • +1Kọ 10:27, 28
  • +Ro 14:23

1 Kọ́ríńtì 8:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:17
  • +Heb 13:9

1 Kọ́ríńtì 8:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:13, 20

1 Kọ́ríńtì 8:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 14:15

1 Kọ́ríńtì 8:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:28, 29

1 Kọ́ríńtì 8:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 18:6; Ro 14:15, 21

Àwọn míì

1 Kọ́r. 8:1Iṣe 15:20, 29
1 Kọ́r. 8:1Ro 14:14; 1Kọ 8:10
1 Kọ́r. 8:11Kọ 8:13; 13:4, 5
1 Kọ́r. 8:4Di 32:21; 2Ọb 19:17, 18; Jer 16:20
1 Kọ́r. 8:4Di 6:4; 32:39
1 Kọ́r. 8:5Sm 82:1, 6; Jo 10:34, 35
1 Kọ́r. 8:61Ti 2:5
1 Kọ́r. 8:6Mal 2:10; Mt 23:9
1 Kọ́r. 8:6Iṣe 17:28; Ro 11:36
1 Kọ́r. 8:6Jo 1:1, 3; Kol 1:15, 16
1 Kọ́r. 8:7Ro 14:14
1 Kọ́r. 8:71Kọ 10:27, 28
1 Kọ́r. 8:7Ro 14:23
1 Kọ́r. 8:8Ro 14:17
1 Kọ́r. 8:8Heb 13:9
1 Kọ́r. 8:9Ro 14:13, 20
1 Kọ́r. 8:11Ro 14:15
1 Kọ́r. 8:121Kọ 10:28, 29
1 Kọ́r. 8:13Mt 18:6; Ro 14:15, 21
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 8:1-13

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

8 Ní báyìí, ní ti oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà:+ A mọ̀ pé gbogbo wa la ní ìmọ̀.+ Ìmọ̀ máa ń gbéra ga, àmọ́ ìfẹ́ ń gbéni ró.+ 2 Tí ẹnì kan bá rò pé òun mọ ohun kan, kò tíì mọ̀ ọ́n bó ṣe yẹ kó mọ̀ ọ́n. 3 Àmọ́ tí ẹnì kan bá nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run, Ọlọ́run mọ ẹni náà.

4 Ní báyìí, ní ti jíjẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà, a mọ̀ pé òrìṣà kò jẹ́ nǹkan kan+ nínú ayé àti pé kò sí Ọlọ́run míì àfi ọ̀kan ṣoṣo.+ 5 Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn tí à ń pè ní ọlọ́run wà, ì báà jẹ́ ní ọ̀run tàbí ní ayé,+ bí ọ̀pọ̀ “ọlọ́run” àti ọ̀pọ̀ “olúwa” ṣe wà, 6 ní tiwa, Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà,+ Baba,+ ọ̀dọ̀ ẹni tí ohun gbogbo ti wá, tí àwa náà sì wà fún un;+ Olúwa kan ló wà, Jésù Kristi, ipasẹ̀ ẹni tí ohun gbogbo fi wà,+ tí àwa náà sì wà nípasẹ̀ rẹ̀.

7 Síbẹ̀, gbogbo èèyàn kọ́ ló mọ̀ bẹ́ẹ̀.+ Ní ti àwọn kan, torí pé òrìṣà ni wọ́n ń bọ tẹ́lẹ̀, wọ́n máa ń wo oúnjẹ tí wọ́n ń jẹ bí ohun tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà,+ èyí sì ń da ẹ̀rí ọkàn wọn tí kò lágbára láàmú.*+ 8 Àmọ́ oúnjẹ kọ́ ló máa mú wa sún mọ́ Ọlọ́run;+ tí a kò bá jẹun, kò bù wá kù, tí a bá sì jẹun, kò sọ wá di ẹni ńlá.+ 9 Ṣùgbọ́n ẹ máa kíyè sára, kí ẹ̀tọ́ tí ẹ ní láti yan ohun tó wù yín má di ohun ìkọ̀sẹ̀ fún àwọn tó jẹ́ aláìlera.+ 10 Nítorí bí ẹnì kan bá rí ìwọ tí o ní ìmọ̀ tí ò ń jẹun nínú tẹ́ńpìlì òrìṣà, ṣé kò ní mú kí ẹ̀rí ọkàn ẹni yẹn le débi pé á lọ jẹ oúnjẹ tí wọ́n fi rúbọ sí òrìṣà? 11 Torí náà, ìmọ̀ rẹ ló mú kí ẹni tó jẹ́ aláìlera ṣègbé, arákùnrin rẹ tí Kristi kú fún.+ 12 Tí ẹ bá ṣẹ àwọn arákùnrin yín lọ́nà yìí, tí ẹ sì kó bá ẹ̀rí ọkàn+ wọn tí kò lágbára, Kristi lẹ ṣẹ̀ sí. 13 Ìdí nìyẹn tó fi jẹ́ pé tí oúnjẹ bá máa mú arákùnrin mi kọsẹ̀, mi ò ní jẹ ẹran mọ́ láé, kí n má bàa mú arákùnrin mi kọsẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́