Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
December 8, 2000
Ìṣòro Àwọn Ọmọdé Ojútùú Náà Rèé O, Nígbẹ̀yìngbẹ́yín!
Àìmọye ọmọ ni a kò fìfẹ́ hàn sí tí a kò sì fẹ́. Àràádọ́ta ọ̀kẹ́ wọn ni òṣì ń ta tí wọ́n sì ń kú ní rèwerèwe lọ́dọọdún. Ọ̀nà àtigbọ́-bùkátà wọn wá dà báyìí?
10 Ojútùú náà Rèé O, Nígbẹ̀yìngbẹ́yín!
13 Ǹjẹ́ Ẹsẹ̀ Máa Ń Rìn ọ́ Wìnnìwìnnì?
18 Ǹjẹ́ o Mọ̀?
30 Wíwo Ayé
31 Atọ́ka Ìdìpọ̀ Kọkànlélọ́gọ́rin Ti jí!
32 “Kíka Ìwé Ìròyìn Yín Ti Mọ́ Mi Lára”
Èé Ṣe Tí Dádì Fi Já Wa Sílẹ̀? 15
Kí ló fà á táwọn bàbá kan fi ń fi ìdílé wọn sílẹ̀? Báwo làwọn ọmọ ṣe lè ṣàkóso inú tó ń bí wọn?
Kí ló dé tí wọ́n fi ṣe inúnibíni sí ọ̀gbẹ́ni yìí tí wọ́n sì tún jù ú sẹ́wọ̀n léraléra ní àwọn ọdún tó tẹ̀ lé Ogun Àgbáyé Kejì?