Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
April 8, 2000
Ìwà Ọmọlúwàbí Dà?
Àwọn èèyàn hu ìwàkiwà gan-an ní ọ̀rúndún ogún. Ṣé ìgbà tiwa nìkan ló rí bẹ́ẹ̀ ni? Àmì kí ló jẹ́?
3 Báwo Ni Ìwà Àwọn Èèyàn Ṣe Rí Láyé Ìsinyìí?
5 Ṣé Ìwà Àwọn Èèyàn Ń Burú Sí I Ju Tàtijọ́ Ni?
9 Àmì Kí Ni Gbogbo Nǹkan Wọ̀nyí Jẹ́?
12 Ǹjẹ́ o Mọ̀?
13 Ayé Kan Tí Sìgá Mímu Ti Di Bárakú Fún
14 Èé Ṣe Tó Fi Yẹ Láti Jáwọ́ Nínú Sìgá Mímu?
20 Wọ́n Ti Gbà Báyìí Pé Àwọn Ò Gba Ẹ̀sìn Míì Láyè
28 Wíwo Ayé
30 Irin Iṣẹ́ Tí A Fi Ń Kọ́ni Ní Ẹ̀tọ́ Ọmọnìyàn
31 Ìgbàgbọ́ Tí Kò Yingin Nígbà Ìpọ́njú
32 April 19, 2000 Ọjọ́ Tó Yẹ Ká Máa Rántí
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Àwọn Ewu Orí Íńtánẹ́ẹ̀tì? 23
Ẹgbàágbèje ọ̀dọ́ ló ń yẹ inú Íńtánẹ́ẹ̀tì wò. Báwo ni wọ́n ṣe lè lo irin iṣẹ́ pàtàkì yìí lọ́nà tó bọ́gbọ́n mu?
Ǹjẹ́ Ó Tọ̀nà Láti Máa Jọ́sìn Jésù? 26
Kí ni Bíbélì sọ nípa èyí?