ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g 4/10 ojú ìwé 29
  • Àtúnyẹ̀wò Fún Ìdílé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àtúnyẹ̀wò Fún Ìdílé
  • Jí!—2010
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Kí Ni Kò Tọ̀nà Nínú Àwòrán Yìí?
  • KÍ LO MỌ̀ NÍPA SÓLÓMỌ́NÌ ỌBA?
  • NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
  • ÌDÁHÙN SÍ ÌBÉÈRÈ
  • Àtúnyẹ̀wò Fún Ìdílé
    Jí!—2011
  • Àtúnyẹ̀wò fún Ìdílé
    Jí!—2010
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2008
  • Kí Ni Ìdáhùn Rẹ?
    Jí!—2009
Àwọn Míì
Jí!—2010
g 4/10 ojú ìwé 29

Àtúnyẹ̀wò Fún Ìdílé

Kí Ni Kò Tọ̀nà Nínú Àwòrán Yìí?

Ka Ẹ́kísódù 12:1-8, 17-20, 24-27; Máàkù 14:12, 22-26; Jòhánù 13:1, 21-30. Kó o wá wo àwòrán Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa tó wà lókè yìí. Àwọn nǹkan wo ni kò tọ̀nà nínú àwòrán náà? Kọ ìdáhùn rẹ sórí àwọn ìlà yìí.

1. ․․․․․

2. ․․․․․

3. ․․․․․

FÚN ÌJÍRÒRÒ:

Kí nìdí tí Jésù fi lo búrẹ́dì tí kò ní ìwúkàrà láti ṣàpẹẹrẹ ara rẹ̀?

AMỌ̀NÀ: Ka 1 Kọ́ríńtì 5:6-8; Hébérù 4:14, 15.

KÍ LO MỌ̀ NÍPA SÓLÓMỌ́NÌ ỌBA?

4. Ta ni ìyá Sólómọ́nì?

AMỌ̀NÀ: Ka 2 Sámúẹ́lì 12:24.

․․․․․

5. Yàtọ̀ sí Sólómọ́nì, ọmọkùnrin mélòó ni ìyá Sólómọ́nì bí fún Dáfídì?

AMỌ̀NÀ: Ka 2 Sámúẹ́lì 11:26, 27; 1 Kíróníkà 3:5.

․․․․․

FÚN ÌJÍRÒRÒ:

Kí nìdí tí Sólómọ́nì fi jẹ́ ọlọ́gbọ́n?

AMỌ̀NÀ: Ka 1 Àwọn Ọba 3:5-14.

Báwo lo ṣe lè jẹ́ ọlọ́gbọ́n?

NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ

Dáhùn àwọn ìbéèrè yìí, kó o sì kọ (àwọn) ẹsẹ Bíbélì tó yẹ sínú àlàfo.

OJÚ ÌWÉ 14 Kí ni “Ìwé Mímọ́” lè ṣe? 2 Tímótì 3:․․․

OJÚ ÌWÉ 15 Kí ni “ìtùnú láti inú Ìwé Mímọ́” lè fún wa? Róòmù 15:․․․

OJÚ ÌWÉ 21 Dídá ronú jẹ́ àmì kí ni? Òwe 1:․․․

OJÚ ÌWÉ 26 Bí ọkùnrin àti obìnrin bá ti ṣègbéyàwó, kí ni wọ́n máa dà? Jẹ́nẹ́sísì 2:․․․

ÌDÁHÙN SÍ ÌBÉÈRÈ

1. Àpọ́sítélì mọ́kànlá ló yẹ kó wà níbẹ̀, kì í ṣe méjìlá.

2. Kò yẹ kí búrẹ́dì yẹn ní ìwúkàrà, torí náà, ṣe ló yẹ kó pẹlẹbẹ.

3. Ẹran ọ̀dọ́ àgùntàn ló yẹ kó jẹ́, kì í ṣe ẹran ẹlẹ́dẹ̀.

4. Bátí-ṣébà.

5. Dáfídì àti Bátí-ṣébà tún bí ọmọkùnrin mẹ́rin míì yàtọ̀ sí Sólómọ́nì.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́