Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July 1, 2010
Ǹjẹ́ O Mọ Orúkọ Ọlọ́run?
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ
3 Ǹjẹ́ Èèyàn Lè Mọ Orúkọ Ọlọ́run?
4 Àwọn Nǹkan Tó Rọ̀ Mọ́ Mímọ Orúkọ Ọlọ́run
5 Ohun Tó Mú Kó Ṣòro Fáwọn Èèyàn Láti Mọ Orúkọ Ọlọ́run
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ TÓ MÁA Ń JÁDE DÉÉDÉ
14 Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Wọn—Obìnrin Náà Gbàdúrà Àtọkànwá sí Ọlọ́run
28 Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . .
29 Sún Mọ́ Ọlọ́run—Rere Tó Wà Lọ́kàn Ẹni Ló Ń Wò
30 Abala Àwọn Ọ̀dọ́—Bí O Ṣe Lè Rí Àwọn Ọ̀rẹ́ Tó Jẹ́ Adúróṣinṣin
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ MÍÌ NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
10 Bó O Ṣe Lè Ṣèrànwọ́ fún Ọ̀rẹ́ Rẹ Kan Tó Ń Ṣàìsàn
19 Ọ̀nà Méje Téèyàn Lè Gbà Jàǹfààní Látinú Bíbélì Kíkà
22 Kí Nìdí Tí Jésù Kò Fi Lọ́wọ́ Nínú Ìṣèlú?
26 Òǹtẹ̀wé Ìjímìjí Kan Gbé Bíbélì Lárugẹ