Atọ́ka Àwọn Àkòrí Ilé Ìṣọ́ 2014
Ó ń tọ́ka sí Ilé Ìṣọ́ tí àpilẹ̀kọ kọ̀ọ̀kan ti jáde
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Bá A Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Kí Àwọn Ọjọ́ Oníwàhálà Tó Dé, 1/15
Bá A Ṣe Lè Máa Tọ́jú Àwọn Àgbàlagbà, 3/15
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa ‘Dá Ẹnì Kọ̀ọ̀kan Lóhùn’? 5/15
Bó O Ṣe Lè Máa Fi Ojú Tó Tọ́ Wo Nǹkan, 3/15
Bó O Ṣe Lè Ṣe Ìpinnu Tó Bọ́gbọ́n Mu Nígbà Ọ̀dọ́, 1/15
‘Ẹ Fetí sí Mi, Kí Ẹ sì Lóye Ìtúmọ̀ Rẹ̀,’ 12/15
Ẹ Máa Bọlá fún Àwọn Àgbàlagbà Tó Wà Láàárín Yín, 3/15
“Ẹ Máa Gbé Èrò Inú Yín Ka Àwọn Nǹkan Ti Òkè,” 10/15
Ẹ Máa Rántí Àwọn Tó Ń Ṣe Iṣẹ́ Ìsìn Alákòókò Kíkún, 9/15
Ẹ̀yin Òbí—Ẹ Máa Kọ́ Àwọn Ọmọ Yín, 9/15
Ẹ̀yin Yóò Di “Ìjọba Àwọn Àlùfáà,” 10/15
Ẹ Yọ̀ Nítorí Ìgbéyàwó Ọ̀dọ́ Àgùntàn! 2/15
Gẹ́gẹ́ Bí Ọ̀tá Ìkẹyìn, Ikú Di Ohun Asán, 9/15
Ìdí Tá A Fi Gbọ́dọ̀ Jẹ́ Mímọ́, 11/15
Ipa Wo Ni Àwọn Obìnrin Ń Kó Nínú Mímú Ìfẹ́ Jèhófà Ṣẹ? 8/15
“Jèhófà Mọ Àwọn Tí Í Ṣe Tirẹ̀,” 7/15
Jèhófà—Olùpèsè àti Aláàbò Wa, 2/15
Jèhófà—Ọ̀rẹ́ Wa Tímọ́tímọ́, 2/15
Jẹ́ Onígboyà—Jèhófà Ni Olùrànlọ́wọ́ Rẹ! 4/15
“Kí Ìjọba Rẹ Dé”—Àmọ́, Nígbà Wo? 1/15
Kò Sí Ẹni Tó Lè Sin Ọ̀gá Méjì, 4/15
Máa Fi Hàn Pé O Ní Ẹ̀mí Ìfara-Ẹni-Rúbọ, 3/15
Máa Fi Ìlànà Pàtàkì Náà Sílò Lóde Ẹ̀rí, 5/15
Máa Gbọ́ Ohùn Jèhófà Níbikíbi Tó O Bá Wà, 8/15
Máa Lo Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run—Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ Yè! 8/15
Máa Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀ Láìka “Ọ̀pọ̀ Ìpọ́njú” Sí, 9/15
Máa Ṣìkẹ́ Àǹfààní Tó O Ní Láti Jẹ́ Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Pẹ̀lú Jèhófà! 10/15
“Nífẹ̀ẹ́ Aládùúgbò Rẹ Gẹ́gẹ́ Bí Ara Rẹ,” 6/15
“Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run Rẹ,” 6/15
Ní Ìgbàgbọ́ Tó Fẹsẹ̀ Múlẹ̀ Ṣinṣin Nínú Ìjọba Ọlọ́run, 10/15
“Nísinsìnyí Ẹ Jẹ́ Ènìyàn Ọlọ́run,” 11/15
Ǹjẹ́ Ó Dá Ẹ Lójú Pé O Wà Nínú Òtítọ́? Kí Nìdí? 9/15
Ǹjẹ́ O “Mòye Ìtúmọ̀ Ìwé Mímọ́”? 12/15
Ǹjẹ́ O Mọyì Bí Jèhófà Ṣe Ń Fìfẹ́ Ṣọ́ Wa? 4/15
Ǹjẹ́ O Mọyì Ohun Tí O Ti Rí Gbà? 12/15
Ǹjẹ́ Ò Ń Bá Ètò Jèhófà Rìn Bó Ṣe Ń Tẹ̀ Síwájú? 5/15
Ǹjẹ́ Ò Ń Rí “Ẹni Tí A Kò Lè Rí”? 4/15
Ọgọ́rùn-ún Ọdún Ìṣàkóso Ìjọba Ọlọ́run—Báwo Ló Ṣe Kàn Ọ́? 1/15
Ran Àwọn Mìíràn Lọ́wọ́ Láti Lo Ẹ̀bùn Wọn ní Kíkún, 6/15
Ṣé Ojú Tí Jèhófà Fi Ń Wo Àìlera Ẹ̀dá Ni Ìwọ Náà Fi Ń Wò Ó? 6/15
Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ìgbàgbọ́ Mósè, 4/15
ÀWỌN ẸLẸ́RÌÍ JÈHÓFÀ
Ẹ̀kọ́ Òtítọ́ Dé Ilẹ̀ Japan, 11/15
Ìpinnu Tí Mo Ṣe Nígbà Tí Mo Wà ní Kékeré, 1/15
Ó “Mọ Ọ̀nà” Náà (G. Pierce), 12/15
Ó Ti Pé Ọgọ́rùn-ún Ọdún Báyìí (Àwòkẹ́kọ̀ọ́ Nípa Ìṣẹ̀dá), 2/15
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Ìwọ̀ Oòrùn Áfíríkà, 1/15
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Micronesia, 7/15
Wọ́n Yọ̀ǹda Ara Wọn ní Taiwan, 10/15
BÍBÉLÌ
Bíbélì Peshitta Lédè Síríákì, 9/1
Bó Ṣe Dé Orílẹ̀-èdè Sípéènì, 3/1
Ṣé Òpìtàn Tí Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ Péye Ni Lúùkù? 1/1
Ṣé Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Lóòótọ́? 2/1
BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ
Bíbélì Ni Wọ́n Fi Dáhùn Gbogbo Ìbéèrè Mi (I. Lamela), 4/1
Ìbọn Máa Ń Wà Lára Mi Níbikíbi Tí Mo Bá Lọ (A. Lugarà), 7/1
Ìlérí Párádísè Yí Ìgbésí Ayé Mi Pa Dà! (I. Vigulis), 2/1
Jèhófà Kò Tíì Gbàgbé Mi (S. Udías), 1/1
Mo Fẹ́ Gba Àwọn Èèyàn Lọ́wọ́ Ìwà Ìrẹ́jẹ àti Ìwà Ipá (A. Touma), 8/1
Tara Mi Nìkan Ni Mo Mọ̀ (C. Bauer), 10/1
ÌBÉÈRÈ LÁTI ỌWỌ́ ÀWỌN ÒǸKÀWÉ
Àwọn wo ni ẹlẹ́rìí méjì? (Ìṣí 11:3-12), 11/15
Báwo la ṣe ń yan àwọn alàgbà àti ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́ sípò? 11/15
“Kì í gbéyàwó, bẹ́ẹ̀ ni a kì í fi wọ́n fúnni nínú ìgbéyàwó” (Lk 20:34-36), 8/15
Kí ló mú kí àwọn Júù ọ̀rúndún kìíní máa “fojú sọ́nà” fún Mèsáyà? (Lk 3:15), 2/15
Kí nìdí tí Rákélì ń sunkún nítorí àwọn ọmọkùnrin rẹ̀? (Jer 31:15), 12/15
Ǹjẹ́ Jèhófà máa jẹ́ kí Kristẹni kan ṣàìní oúnjẹ tí ó tó? (Sm 37:25; Mt 6:33), 9/15
Ṣó yẹ kéèyàn máa fi iná sun òkú? 6/15
ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI ÀNÍMỌ́ KRISTẸNI
Àwọn Ìbátan Wa Tí Kì í Ṣe Ẹlẹ́rìí, 3/15
Gba Oúnjẹ “Ní Àkókò Tí Ó Bẹ́tọ̀ọ́ Mu,” 8/15
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí O Máa Gbàdúrà? 4/1
‘Mú Ipa Ọ̀nà Jọ̀lọ̀’ Kó O Lè Tẹ̀ Síwájú, 6/15
Ǹjẹ́ “Bẹ́ẹ̀ Ni” Rẹ Kì Í Di “Bẹ́ẹ̀ Kọ́”? 3/15
Ǹjẹ́ Ò Ń ‘Nàgà fún Iṣẹ́ Àtàtà’? 9/15
Ǹjẹ́ Ó Yẹ Kó O Yí Èrò Rẹ Pa Dà? 12/15
‘Oúnjẹ Mi Ni Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọ́run,’ 5/15
‘Pa Dà Kí O sì Fún Àwọn Arákùnrin Rẹ Lókun,’ 8/15
Ran Àwọn Kristẹni Tí Ọkọ Tàbí Ìyàwó Wọn Kọ̀ Sílẹ̀ Lọ́wọ́, 6/15
ÌTÀN ÌGBÉSÍ AYÉ
Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Nígbèésí Ayé Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìjọba Ọlọ́run (M. Olson), 10/15
Baba Kú Àmọ́, Baba Kù (G. Lösch), 7/15
Bí Mo Tiẹ̀ Jẹ́ Aláìlera, Okun Inú Ń Gbé Mi Ró (M. Morlans), 3/1
Ibi Tí Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Alákòókò Kíkún Gbé Mi Dé (R. Wallen), 4/15
Ìgbésí Ayé Mi Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìsìn Ọlọ́run Mérè Wá (P. Carrbello), 9/1
Jèhófà Ti Ràn Mí Lọ́wọ́ (K. Little), 5/15
JÈHÓFÀ
Bó O Ṣe Lè Kọ́ Àwọn Ọmọ Rẹ Láti Nífẹ̀ẹ́ Ọlọ́run, 12/1
Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìnilára, 2/1
Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Fàyè Gba Ìyà Tó Ń Jẹ Aráyé, 1/1
Ǹjẹ́ Ọlọ́run Bìkítà Nípa Rẹ? 8/1
Ohun Tí Ọlọ́run Ti Ṣe fún Ẹ, 3/1
Ojú Tó Fi Ń Wo Ìwà Ìrẹ́jẹ, 1/1
Ó Ń Bù Kún Àwọn Tó Ní Ẹ̀mí Ìmúratán, 12/15
JÉSÙ KRISTI
Àǹfààní Tí Ikú Jésù Ṣe fún Wa, 3/1
Báwo Ló Ṣe Yẹ Ká Máa Rántí Ikú Jésù? 3/1
Ìṣẹ̀lẹ̀ Pàtàkì Kan Tó Yẹ Kó Ṣojú Ẹ (Ìrántí Ikú Kristi), 3/1
Kí Ló Máa Ṣe Lọ́jọ́ Iwájú? 4/1
Ó Jí Àwọn Èèyàn Dìde, Kí Nìdí? 11/1
Ọ̀KAN-Ọ̀-JỌ̀KAN
Àwọn Mẹ́ta Tó Wá Òtítọ́ Ní Ọgọ́rùn-ún Ọdún Kẹrìndínlógún, 6/1
Bí Àwọn Atukọ̀ Òkun Ṣe Ń Ṣe Ọkọ̀ Òkun Wọn Kí Omi Má Bàa Wọnú Rẹ̀, 7/1
Bí O Ṣe Lè Bá Àwọn Ọmọ Rẹ Wí, 7/1
Bí Wọ́n Ṣe Máa Ń Fi Kànnàkànnà Jagun Láyé Àtijọ́, 5/1
Bí Wọ́n Ṣe Ń Fi Ọrẹ Ṣètìlẹyìn Nínú Tẹ́ńpìlì, 1/1
Bí Wọ́n Ṣe Ń Tọ́jú Ẹja Láyé Àtijọ́ Kó Má Bàa Bàjẹ́, 7/1
Búrẹ́dì Tí Ń Fúnni Ní Ìyè, 6/1
‘Èmi Kò Lè Hùwà Búburú Ńlá Yìí’ (Jósẹ́fù), 11/1
“Ẹ Jọ̀wọ́, Ẹ Fetí sí Àlá Tí Mo Lá” (Jósẹ́fù), 8/1
Fífarada Ìwà Ìrẹ́jẹ (Èlíjà), 2/1
Ìdí Tí Ọlọ́run Fi Dá Ilẹ̀ Ayé, 6/1
Ìgbà Tí Ìjọba Ọlọ́run Bẹ̀rẹ̀, 10/1, 11/1
‘Ìjìnlẹ̀ Òye Máa Ń Dẹwọ́ Ìbínú,’ 12/1
Ìjọba Ọlọ́run—Àǹfààní Tó Máa Ṣe Ẹ́, 10/1
Ìrètí Wo Ló Wà Fún Àwọn Baba Ńlá Tó Ti Kú? 6/1
Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti Gbọn Ẹ̀wù Ya? 4/15
Kí Nìdí Tí Nǹkan Burúkú Fi Ń Ṣẹlẹ̀ Sáwọn Èèyàn Rere? 7/1
Kí Nìdí Tí Wọ́n Fi Máa Ń Ṣẹ́ Ẹsẹ̀ Àwọn Tí Wọ́n Fẹ́ Pa? 5/1
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Gbàdúrà? Báwo La Ṣe Lè Gbà Á? 7/1
Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Gbàdúrà Pé Kí Ìjọba Ọlọ́run Dé? 10/1
Ǹjẹ́ Òfin Tí Ọlọ́run Fún Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Bá Ẹ̀tọ́ Mu? 9/1
Ó Fara Da Ọgbẹ́ Ọkàn (Màríà), 5/1
Ogun Tó Da Ayé Rú (Ogun Àgbáyé Kìíní), 2/1
Ojú Tí Ọlọ́run Fi Ń Wo Sìgá Mímu, 6/1
Ṣé Àwọn Èèyàn Ò Ní Ba Ayé Yìí Jẹ́ Kọjá Àtúnṣe? 9/1