Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Ọ̀sẹ̀ Tó Bẹ̀rẹ̀ ní February 13
Ọ̀SẸ̀ TÓ BẸ̀RẸ̀ NÍ FEBRUARY 13
Orin 7 àti Àdúrà
□ Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ:
bt orí 16 ìpínrọ̀ 13 sí 18 (25 min.)
□ Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run:
Bíbélì kíkà: Aísáyà 52-57 (10 min.)
No. 1: Aísáyà 56:1-12 (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
No. 2: Báwo Ni Àpẹẹrẹ Ìdúróṣinṣin Pétérù Ṣe Ṣe Wá Láǹfààní?—Jòh. 6:68, 69 (5 min.)
No. 3: Ohun Tó Jẹ́ Òótọ́ Nípa Wíwà Ọlọ́run—td 34B (5 min.)
□ Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn:
5 min: Àwọn Ìfilọ̀.
10 min: Kọ́ Bí A Ṣe Ń Jẹ́ Olùkọ́ Tó Múná Dóko—Apá 1. Àsọyé tá a gbé ka ìwé Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 56, ìpínrọ̀ 1, sí ojú ìwé 57, ìpínrọ̀ 2.
10 min: Ọlọ́run Ń Mú Kí Ó Máa Dàgbà. (1 Kọ́r. 3:6) Àsọyé tá a gbé ka Ilé Ìṣọ́ March 15, 2004, ojú ìwé 13, ìpínrọ̀ 14 sí ojú ìwé 14, ìpínrọ̀ 21. Ní kí àwọn ará sọ ẹ̀kọ́ tí wọ́n kọ́.
10 min: “Ṣètò Báyìí Láti Ṣe Púpọ̀ Sí I Lẹ́nu Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Rẹ.” Ìbéèrè àti Ìdáhùn. Nígbà tẹ́ ẹ bá dé ìpínrọ̀ 3, ní kí alábòójútó iṣẹ́ ìsìn sọ̀rọ̀ nípa ètò tí ìjọ ti ṣe fún ìpàdé fún iṣẹ́ ìsìn pápá ní oṣù March, April àti May.
Orin 107 àti Àdúrà