ORIN SÓLÓMỌ́NÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
Ọ̀DỌ́BÌNRIN ṢÚLÁMÁÍTÌ WÀ NÍNÚ ÀGỌ́ ỌBA SÓLÓMỌ́NÌ (1:1–3:5)
Ọ̀DỌ́BÌNRIN ṢÚLÁMÁÍTÌ WÀ NÍ JERÚSÁLẸ́MÙ (3:6–8:4)
-
Àwọn ọmọbìnrin Síónì (6-11)
Sólómọ́nì àti àwọn tó ń tẹ̀ lé e
-
Ọ̀DỌ́BÌNRIN ṢÚLÁMÁÍTÌ PA DÀ, Ó JẸ́ ADÚRÓTINI (8:5-14)
-
Àwọn arákùnrin ọ̀dọ́bìnrin náà (5a)
‘Ta nìyí, tó fara ti olólùfẹ́ rẹ̀?’
Ọ̀dọ́bìnrin (5b-7)
“Ìfẹ́ lágbára bí ikú” (6)
Àwọn arákùnrin ọ̀dọ́bìnrin náà (8, 9)
“Tó bá jẹ́ ògiri, . . . àmọ́ tó bá jẹ́ ilẹ̀kùn, . . .” (9)
Ọ̀dọ́bìnrin (10-12)
“Ògiri ni mí” (10)
Olùṣọ́ àgùntàn (13)
‘Jẹ́ kí n gbọ́ ohùn rẹ’
Ọ̀dọ́bìnrin (14)
“Yára bí egbin”
-