JEREMÁYÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ọlọ́run yan Jeremáyà láti jẹ́ wòlíì (1-10)
Ìran nípa igi álímọ́ńdì (11, 12)
Ìran nípa ìkòkò ìsebẹ̀ (13-16)
Ọlọ́run fún Jeremáyà lágbára kó lè jẹ́ iṣẹ́ tó rán an (17-19)
2
3
Bí ìpẹ̀yìndà Ísírẹ́lì ṣe burú tó (1-5)
Ísírẹ́lì àti Júdà jẹ̀bi àgbèrè (6-11)
Ọlọ́run ní kí wọ́n ronú pìwà dà (12-25)
4
Ìrònúpìwàdà ń mú ìbùkún wá (1-4)
Àjálù yóò wá láti àríwá (5-18)
Àjálù tó ń bọ̀ kó ẹ̀dùn ọkàn bá Jeremáyà (19-31)
5
Àwọn èèyàn náà kò gba ìbáwí Jèhófà (1-13)
Ìparun ń bọ̀, àmọ́ kì í ṣe ìparun pátápátá (14-19)
Jèhófà pe àwọn èèyàn náà wá jíhìn (20-31)
6
Ọ̀tá máa tó dó ti Jerúsálẹ́mù (1-9)
Ìbínú Jèhófà lórí Jerúsálẹ́mù (10-21)
Ọ̀tá ya wọ ilẹ̀ náà láti àríwá (22-26)
Jeremáyà máa di ẹni tó ń yọ́ wúrà àti fàdákà mọ́ (27-30)
7
Ìgbẹ́kẹ̀lé asán nípa tẹ́ńpìlì Jèhófà (1-11)
Tẹ́ńpìlì náà yóò dà bíi Ṣílò (12-15)
Ọlọ́run kọ ìjọsìn wọn (16-34)
8
Àwọn èèyàn náà ń ṣe ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn ń ṣe (1-7)
Ǹjẹ́ ọgbọ́n lè wà láìsí ọ̀rọ̀ Jèhófà? (8-17)
Jeremáyà kédàárò lórí ìṣubú Júdà (18-22)
9
Ìbànújẹ́ Jeremáyà pọ̀ gan-an (1-3a)
Jèhófà pe Júdà wá jíhìn (3b-16)
Ìdárò lórí Júdà (17-22)
Máa yangàn torí pé o mọ Jèhófà (23-26)
10
Àwọn ọlọ́run orílẹ̀-èdè àti Ọlọ́run alààyè (1-16)
Ìparun àti ìgbèkùn ń bọ̀ lọ́nà (17, 18)
Inú Jeremáyà bà jẹ́ (19-22)
Àdúrà tí wòlíì náà gbà (23-25)
11
Júdà da májẹ̀mú Ọlọ́run (1-17)
Jeremáyà dà bí ọ̀dọ́ àgùntàn tí wọ́n fẹ́ lọ pa (18-20)
Àtakò tí àwọn ará ìlú Jeremáyà ṣe (21-23)
12
13
Àmùrè aṣọ ọ̀gbọ̀ tó bà jẹ́ (1-11)
Ọlọ́run máa fọ́ àwọn ìṣà wáìnì (12-14)
Júdà alágídí máa lọ sí ìgbèkùn (15-27)
14
Ọ̀dá, ìyàn àti idà (1-12)
Ọlọ́run dá àwọn wòlíì èké lẹ́bi (13-18)
Jeremáyà sọ ẹ̀ṣẹ̀ tí àwọn èèyàn náà dá (19-22)
15
Jèhófà kò ní yí ìdájọ́ rẹ̀ pa dà (1-9)
Jeremáyà mú ẹjọ́ rẹ̀ wá (10)
Ohun tí Jèhófà sọ (11-14)
Àdúrà Jeremáyà (15-18)
Jèhófà fún Jeremáyà lágbára (19-21)
16
Jeremáyà kò gbọ́dọ̀ gbéyàwó tàbí kó ṣọ̀fọ̀, kò sì gbọ́dọ̀ jẹ àsè (1-9)
Ìjìyà, lẹ́yìn náà ìpadàbọ̀sípò (10-21)
17
Júdà ti jingíri sínú ẹ̀ṣẹ̀ (1-4)
Ìbùkún tó wà nínú gbígbẹ́kẹ̀lé Jèhófà (5-8)
Ọkàn tó ń tanni jẹ (9-11)
Jèhófà jẹ́ ìrètí Ísírẹ́lì (12, 13)
Àdúrà Jeremáyà (14-18)
Jẹ́ kí Sábáàtì wà ní mímọ́ (19-27)
18
Amọ̀ tó wà lọ́wọ́ amọ̀kòkò (1-12)
Jèhófà kẹ̀yìn sí Ísírẹ́lì (13-17)
Wọ́n gbìmọ̀ ibi sí Jeremáyà; ó ké pe Ọlọ́run (18-23)
19
20
21
22
23
Àwọn olùṣọ́ àgùntàn rere àti búburú (1-4)
Ààbò lábẹ́ “èéhù kan tí ó jẹ́ olódodo” (5-8)
Ọlọ́run dá àwọn wòlíì èké lẹ́bi (9-32)
“Ẹrù tó wúwo” látọ̀dọ̀ Jèhófà (33-40)
24
25
26
27
28
29
30
31
32
33
Ìlérí ìpadàbọ̀sípò (1-13)
Ààbò lábẹ́ “èéhù òdodo” (14-16)
Májẹ̀mú tí Ọlọ́run bá Dáfídì àti àwọn àlùfáà dá (17-26)
34
35
36
Jeremáyà ń sọ ohun tí wọ́n ń kọ sínú àkájọ ìwé (1-7)
Bárúkù ka ọ̀rọ̀ inú àkájọ ìwé sókè (8-19)
Jèhóákímù dáná sun àkájọ ìwé náà (20-26)
A tún ọ̀rọ̀ náà kọ sínú àkájọ ìwé tuntun (27-32)
37
Àwọn ará Kálídíà ṣígun lọ fúngbà díẹ̀ (1-10)
Wọ́n fi Jeremáyà sẹ́wọ̀n (11-16)
Sedekáyà pàdé Jeremáyà (17-21)
38
Wọ́n ju Jeremáyà sínú kòtò omi (1-6)
Ebedi-mélékì gba Jeremáyà sílẹ̀ (7-13)
Jeremáyà rọ Sedekáyà pé kó juwọ́ sílẹ̀ (14-28)
39
40
Nebusarádánì jẹ́ kí Jeremáyà lọ ní òmìnira (1-6)
A yan Gẹdaláyà ṣe olórí ilẹ̀ náà (7-12)
Wọ́n dìtẹ̀ Gẹdaláyà (13-16)
41
42
43
44
45
46
47
48
49
Àsọtẹ́lẹ̀ lórí àwọn ọmọ Ámónì (1-6)
Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Édómù (7-22)
Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Damásíkù (23-27)
Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Kédárì àti Hásórì (28-33)
Àsọtẹ́lẹ̀ lórí Élámù (34-39)
50
51
52
Sedekáyà ṣọ̀tẹ̀ sí Bábílónì (1-3)
Nebukadinésárì dó ti Jerúsálẹ́mù (4-11)
Ìparun Jerúsálẹ́mù àti tẹ́ńpìlì rẹ̀ (12-23)
Wọ́n kó àwọn èèyàn lọ sí ìgbèkùn ní Bábílónì (24-30)
Wọ́n dá Jèhóákínì sílẹ̀ lẹ́wọ̀n (31-34)