FÍLÍPÌ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Ìkíni (1, 2)
Ọpẹ́ ni fún Ọlọ́run; Àdúrà Pọ́ọ̀lù (3-11)
Ìhìn rere ń tẹ̀ síwájú kódà lójú wàhálà (12-20)
Ààyè mi jẹ́ ti Kristi, ikú mi jẹ́ èrè (21-26)
Ẹ máa hùwà lọ́nà tó yẹ ìhìn rere (27-30)
2
Ìrẹ̀lẹ̀ Kristẹni (1-4)
Ìrẹ̀lẹ̀ Kristi àti ìgbéga rẹ̀ (5-11)
Ẹ máa ṣiṣẹ́ ìgbàlà yín yọrí (12-18)
Ó rán Tímótì àti Ẹpafíródítù (19-30)
3
4
Ìṣọ̀kan, ayọ̀, èrò tí ó tọ́ (1-9)
Pọ́ọ̀lù mọyì ẹ̀bùn àwọn ará Fílípì (10-20)
Ìkíni tó fi parí ọ̀rọ̀ rẹ̀ (21-23)