ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g04 5/8 ojú ìwé 1-2
  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
  • Jí!—2004
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ibi Iṣẹ́ Àbí Ojú Ogun?
    Jí!—2004
  • Ṣé Ọlọ́run Máa Ń Dá Àwọn Èèyàn Lóró Nínú Iná Ọ̀run Àpáàdì?
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
  • Ohun Tó Máa Ń mú Kí Wọ́n Dájú Sọni
    Jí!—2004
  • Fífi Ìbálòpọ̀ Fòòró Ẹni—Ìṣòro Kárí Ayé Kan
    Jí!—1996
Àwọn Míì
Jí!—2004
g04 5/8 ojú ìwé 1-2

Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

May 8, 2004

Bí Wọ́n Bá Dájú Sọ Ọ́ Níbi Iṣẹ́ Kí Lo Lè Ṣe?

Àwọn ìlànà inú Bíbélì lè ràn ọ́ lọ́wọ́ láti kojú ìfòòró-ẹni lẹ́nu iṣẹ́ kó o sì ṣẹ́pá rẹ̀ pẹ̀lú.

3 Ibi Iṣẹ́ Àbí Ojú Ogun?

5 Ohun Tó Máa Ń mú Kí Wọ́n Dájú Sọni

7 Wíwà Ní Ìrẹ́pọ̀ Níbi Iṣẹ́

10 Bí Ìgbàgbọ́ Ṣe Ran Ìdílé Kan Lọ́wọ́ Nígbà Ìpọ́njú

12 ‘Àwọn Àwòrán Yìí Nítumọ̀ Gan-⁠an Ni’

13 Ǹjẹ́ Ó Ní Nǹkan Tí ìrètí Lè Ṣe fún Wa?

14 Kí Nìdí Tá A Fi Nílò Ìrètí?

16 Lílo Òmìnira Kristẹni Lọ́nà Yíyẹ

17 O Lè Gbara Rẹ Lọ́wọ́ Ẹ̀mí Pé Nǹkan Ò Ní Dára

19 Ibo Lo Ti Lè Rí Ìrètí Tòótọ́?

23 Ṣé Nítorí Àtiṣoge Nìkan Ni?

30 Kí Lo Lè Ṣe Bí Ọmọ Rẹ Bá Ń ké Ṣáá?

31 Mi Ò Jẹ́ Mu Sìgá!

32 Wo “Ilẹ̀ Dáradára” Náà

Ṣó Yẹ Kí N Máa Lọ Ságbo Ijó Alẹ́? 25

Àwọn agbo ijó alẹ́ túbọ̀ ń pọ̀ sí i, àmọ́ ṣé ewu wà níbẹ̀?

Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ka Ìgbéyàwó sí Ohun Mímọ́? 28

Àṣeyọrí ìgbéyàwó rẹ sinmi lórí ojú tó o fi ń wò ó.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́