Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
October–December 2006
Tẹlifíṣọ̀n—Ipa Wo Ló Ń Ní Lórí Ìgbésí Ayé Rẹ?
Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé tẹlifíṣọ̀n ló ń nípa tó lágbára jù lórí ìrònú àti ìṣe àwọn èèyàn. Ipa wo ló ń ní lórí rẹ?
3 Ṣé Tẹlifíṣọ̀n Ń Jani Lólè Àkókò Lóòótọ́?
4 Tẹlifíṣọ̀n “Olùkọ́ Tó Ń kọ́ Wa Láìmọ̀”
8 Béèyàn Ṣe Lè Pinnu Ìwọ̀n Táá Máa Wò
10 Bó o ṣe lè ran ọmọbìnrin rẹ lọ́wọ́ láti múra sílẹ̀ de Ìgbà Tó Máa Bẹ̀rẹ̀ sí Í Ṣe Nǹkan Oṣù
14 Ọmọdé Kan Tí Ìgbàgbọ́ Ẹ̀ Lágbára
16 Wíwo Ayé
20 Báwo ni mo ṣe lè ṣàlàyé ohun tí mo gbà gbọ́ nípa ìṣẹ̀dá?
23 Ṣé Ohun Tó Bá Wù Ọ́ Lo Lè Gbà Gbọ́?
28 Ṣé Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Ta Ko Àkọsílẹ̀ Inú Jẹ́nẹ́sísì?
32 Àràádọ́ta Ọ̀kẹ́ Èèyàn Ló Máa Lọ Síbẹ̀ Ṣé Ìwọ Náà Á Lọ?
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Ran Àwọn Tó Di Aláìní Lọ́wọ́? 17
Lóde òní, ọ̀pọ̀ ọ̀dọ́ ló ń yọ̀ǹda ara wọn fúnṣẹ́. Kí ló ń mú kí wọ́n ṣe bẹ́ẹ̀? Kí sì lohun tó ń ṣèrànlọ́wọ́ jù lọ lára ohun tí wọ́n ń yọ̀ǹda?
Ṣáwọn Èèyàn Máa Ń Di Áńgẹ́lì Lẹ́yìn Tí Wọ́n Bá Kú? 26
Èrò tó wọ́pọ̀ lèyí, àmọ́ kí ni Bíbélì sọ lórí ọ̀rọ̀ náà?