Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
March–April 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Ọ̀RỌ̀ PÀTÀKÌ FÚN ÀWỌN TÓ FẸ́ ṢÍ LỌ SÍ ÌLÚ MÍÌ 6 sí 9
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ . . .
Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífi Ọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?
Téèyàn ò bá ṣe àṣejú nídìí fífi ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ lórí fóònù, ó lè máa fi bá àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ sọ̀rọ̀. Àmọ́ téèyàn bá ṣe àṣejù nídìí rẹ̀, ó lè ba ara rẹ̀ lórúkọ jẹ́, ó sì lè di ẹni burúkú lọ́dọ̀ àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀. Kà nípa irú àwọn tó o lè máa fi ọ̀rọ̀ ránṣẹ́ sí, irú ọ̀rọ̀ tó o lè máa kọ ránṣẹ́ àti ìgbà tó o lè máa kọ ọ̀rọ̀ ránṣẹ́.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN ỌMỌDÉ)