Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May–June 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Bó O Ṣe Lè Jẹ́ Bàbá Rere 3 SÍ 6
7 Bí Ọkọ Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Lílu Ìyàwó Rẹ̀
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Báwo Ni Mo Ṣe Lè Jáwọ́ Nínú Fífi Nǹkan Falẹ̀?
Ṣé ó máa ń wù ẹ́ pé kó o tètè parí àwọn iṣẹ́ ilé àtàwọn iṣẹ́ àṣetiléwá rẹ? Àfi kó o tètè máa jára mọ́ ọn! Àpilẹ̀kọ yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ kódà tó bá dà bíi pé iṣẹ́ náà fẹ́ pọ̀ jù fún ẹ, tí kò bá wù ẹ́ ṣe tàbí tọ́wọ́ rẹ bá ń dí gan-an.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN ỌMỌDÉ)