Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July–August 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
ÀPILẸ̀KỌ TÓ DÁ LÓRÍ ÀKÒRÍ Ẹ̀YÌN ÌWÉ: Bó O Ṣe Lè Bọ́ Lọ́wọ́ Àwọn Ọ̀daràn 6 SÍ 9
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ | www.jw.org/yo
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ
Bí Ara Mi Kò Bá Yá Ńkọ́? (Apá Kìíní)
Ọmọbìnrin kan tó ń jẹ́ Yeimy sọ pé: “Mi ò tíì ju ọmọ ọdún mọ́kànlá [11] péré lọ tí mo ti wà lórí kẹ̀kẹ́ arọ. Mi ò lè ṣe àwọn nǹkan pẹ́ẹ́pẹ̀ẹ̀pẹ́, irú bíi kí n gbé nǹkan tí kò wúwo.” Kà nípa ohun tí Yeimy àtàwọn ọ̀dọ́ mẹ́ta míì ṣe sí ìṣòro àìlera wọn.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN ỌMỌDÉ)