Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May–June 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Ǹjẹ́ O Gbà Pé Ọlọ́run Wà?—Tó O Bá Gbà Àǹfààní Wo Ló Máa Ṣe Ẹ́?
OJÚ ÌWÉ 3-6
7 Ohun tó ń lọ Láyé Ohun Tó Ń Ṣẹlẹ̀ Nílẹ̀ Áfíríkà
8 Ìrànlọ́wọ́ fún Ìdílé Bó O Ṣe Lè Ní Àjọṣe Tó Dáa Pẹ̀lú Àwọn Àna Rẹ
10 ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÌDÍLÉ Ohun Tó O Lè Ṣe Tó Bá Ń Ṣe Ẹ́ Bí I Pé O Kò Ní Ọ̀rẹ́
12 OJÚ ÌWÒYE BÍBÉLÌ Àwọn Ẹranko?
14 Ojú Ìwòye Bíbélì Tẹ́tẹ́ Títa
16 TA LÓ ṢIṢẸ́ ÀRÀ YÌÍ? Iṣẹ́ Tí Irun Imú Ológbò Ń Ṣe
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Ohun Táwọn Ojúgbà Ẹ Sọ Fífi Ọ̀ranyàn Báni Tage
Nínú fídíò yìí, wàá gbọ́ ohun tí àwọn ọ̀dọ́ sọ pé àwọn ṣe nígbà tí àwọn kan fẹ́ máa bá wọn tage lọ́ranyàn àti ohun tó o lè ṣe tí àwọn èèyàn kò fi ní máa fi irú nǹkan bẹ́ẹ̀ lọ̀ ẹ́.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
CHILDREN
Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà Máa Wà ní Mímọ́ Tónítóní
é àwọn ọmọ rẹ ti wo fídíò tó dùn tó sì ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́, irú bíi, Máa Wà Ní Mímọ́ Tónítóní.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)