NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
July 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
Ǹjẹ́ O Lè Pinnu Bí Ìgbésí Ayé Rẹ Ṣe Máa Rí?
Ohun tó jẹ́ ìṣòro: Ìṣòro Tó Kọjá Agbára Wa
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀPILẸ̀KỌ
Àpilẹ̀kọ yìí sọ ohun mẹ́ta tó o lè ṣe láti mú ìbànújẹ́ kúrò lọ́kàn.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
FÍDÍÒ
Nínú fídíò àwọn ọmọdé yìí, Kọ́là fẹ́ mú nǹkan tí kì í ṣe tirẹ̀. Kí ni kò jẹ́ kí Kọ́lá mú nǹkan náà mọ́?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)