Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
No. 1 2016
© 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
9 Kí Ló Máa Ń Fa Wàhálà Nínú Ilé?
10 Bí Ẹ Ṣe Lè Dín Wàhálà Kù Nínú Ilé
12 Bí Ẹ Ṣe Lè Mú Kí Àlàáfíà Wà Nínú Ilé
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN ÀPILẸ̀KỌ
Nípa Wa
Wò ó bóyá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà gbà pé àwọn nìkan ló máa rí ìgbàlà.
Tún wo ohun tí Bíbélì sọ nípa ọ̀pọ̀ ìbéèrè tó máa ń jẹ àwọn èèyàn lọ́kàn, àwọn ìbéèrè bíi:
(Wo abẹ́ NÍPA WA > ÀWỌN ÌBÉÈRÈ TÁWỌN ÈÈYÀN Ń BÉÈRÈ)
FÍDÍÒ
Àwọn Ọmọdé
Wo àwọn fídíò tó ń kọ́ni láwọn ẹ̀kọ́ àtàtà, irú bí ìdí tó fi yẹ ká máa dárí jini ní fàlàlà.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)