Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
NÍNÚ ÌTẸ̀JÁDE YÌÍ
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Wo fídíò tó sọ nípa ojú tí àwọn ọ̀dọ́ fi wo níná owó.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Àwọn ọmọdé méjì gba ohun ìṣeré lọ́wọ́ àwọn òbí wọn.
Ṣé wọ́n á jọ fi àwọn ẹ̀bùn náà ṣeré papọ̀?
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)