ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • g21 No. 2 ojú ìwé 15
  • Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I Lórí Ìkànnì JW.ORG

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Kẹ́kọ̀ọ́ Sí I Lórí Ìkànnì JW.ORG
  • Jí!—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ohun Tó Lè Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́
    Jí!—2020
  • Ohun Míì Tó Máa Ran Ìdílé Lọ́wọ́
    Jí!—2018
  • Wàá Rí Ìmọ̀ràn Tó Máa Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Lórí Ìkànnì JW.ORG
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ìkànnì Wa Lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì—Ó Wúlò Fún Àwa Àtàwọn Ẹlòmíì
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2012
Àwọn Míì
Jí!—2021
g21 No. 2 ojú ìwé 15

Kẹ́kọ̀ọ́ Sí i Lórí Ìkànnì Jw.Org

Èwo nínú àwọn ìbéèrè yìí lo fẹ́ mọ ìdáhùn ẹ̀?

Ọkọ àtìyàwó ń tẹ fóònù bí wọ́n ṣe ń jẹun.

Báwo ni mo ṣe lè mú kí ìdílé mi túbọ̀ láyọ̀?

Wo àpilẹ̀kọ náà, “Bó Ò Ṣe Ní Jẹ́ Kí Ẹ̀rọ Ìgbàlódé Gbà Ẹ́ Lọ́kàn.”

Bàbá kan ń kọ́ ọmọ ẹ̀ bó ṣe máa lo fóònù tó ń lo Íńtánẹ́ẹ̀tì láìséwu.

Báwo ni mo ṣe lè kọ́ àwọn ọmọ mi kí wọ́n lè níwà tó dáa?

Wo àpilẹ̀kọ náà, “Kọ́ Àwọn Ọmọdé Bí Wọ́n Ṣe Lè Máa Fọgbọ́n Lo Fóònù.”

Ọkùnrin kan ń sọ bójú ọjọ́ ṣe máa rí láàárín ọjọ́ méje.

Kí ni mo lè ṣe kí n má bàa máa bẹ̀rù ọjọ́ ọ̀la?

Wo ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ náà, “Kí Ló Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú?”

Bíbélì lè ran ìwọ àti ìdílé ẹ lọ́wọ́ kẹ́ ẹ lè gbádùn ayé yín ní báyìí, kí ọkàn yín sì balẹ̀ pé ọ̀la ń bọ̀ wá dáa.

NǸKAN MÍÌ TÓ WÀ LÓRÍ JW.ORG: Ohun Tá A Fi Ń Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Ọ̀fẹ́ ni. O ò sì ní forúkọ sílẹ̀.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́