ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • ll apá 11 ojú ìwé 24-25
  • Ṣé Jèhófà Máa Ń Tẹ́tí Gbọ́ Wa?

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ṣé Jèhófà Máa Ń Tẹ́tí Gbọ́ Wa?
  • Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sísún Mọ́ Ọlọrun Nínú Àdúrà
    Kí Ni Ọlọ́run Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
  • Àǹfààní Pàtàkì Ni Àdúrà Jẹ́
    Kí Ni Bíbélì Kọ́ Wa?
  • Máa Gbàdúrà Kó O Lè Túbọ̀ Sún Mọ́ Ọlọ́run
    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!—Ìjíròrò Látinú Bíbélì
  • Nípa Àwọn Àdúrà Tí Ọlọ́run Ń Gbọ́
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2009
Àwọn Míì
Tẹ́tí sí Ọlọ́run Kó O Lè Wà Láàyè Títí Láé
ll apá 11 ojú ìwé 24-25

APÁ 11

Ṣé Jèhófà Máa Ń Tẹ́tí Gbọ́ Wa?

Ó dájú pé Ọlọ́run máa ń gbọ́ àdúrà wa. 1 Pétérù 3:12

Ìtẹ́ Jèhófà ní ọ̀run

“Olùgbọ́ àdúrà” ni Jèhófà. (Sáàmù 65:2) Ó fẹ́ ká máa sọ gbogbo ohun tó wà lọ́kàn wa fún òun.

Ọkùnrin kan ń gbàdúrà

Jèhófà ni kí o máa gbàdúrà sí, má ṣe gbàdúrà sí ẹlòmíì.

  • Jésù kọ́ wa bí a ṣe lè máa gbàdúrà.​—Mátíù 6:​9-15.

  • Àdúrà àwọn wo ni Ọlọ́run máa ń gbọ́?​—Sáàmù 145:​18, 19.

A lè mẹ́nu kan ọ̀pọ̀ nǹkan nínú àdúrà wa. 1 Jòhánù 5:14

Jésù àtàwọn ọ̀kẹ́ méje ó lé ẹgbàajì nínú Ìjọba náà

Máa gbàdúrà pé kí ìfẹ́ Ọlọ́run ṣẹ ní ọ̀run àti ní ayé.

Máa gbàdúrà ní orúkọ Jésù kí o lè fi hàn pé o mọyì ohun tó ṣe fún ọ.

Kristẹni kan gbára lé Jèhófà pé kó ran òun lọ́wọ́ láti bójú tó ìdílé òun, kó sì ran òun lọ́wọ́ láti máa ṣohun tó dáa

Máa bẹ Jèhófà pé kó jẹ́ kí o lè máa ṣe ohun tó dáa. O tún lè bẹ̀bẹ̀ fún oúnjẹ, iṣẹ́, ilé gbígbé, aṣọ àti ìlera rẹ nínú àdúrà.

  • Jèhófà máa ń tẹ́tí sí àwọn èèyàn tó ń ṣe ohun tó tọ́.​—Òwe 15:29.

  • Má ṣe máa ṣàníyàn.​—Fílípì 4:​6, 7.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́