Saturday
‘Wọ́n ń fi ìgboyà púpọ̀ sí i hàn láti sọ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run láìbẹ̀rù’—FÍLÍPÌ 1:14
ÒWÚRỌ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 76 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ẹ Jẹ́ Onígboyà . . .
Ẹ̀yin Akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì (Ìṣe 8:35, 36; 13:48)
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́ (Sáàmù 71:5; Òwe 2:11)
Ẹ̀yin Akéde (1 Tẹsalóníkà 2:2)
Ẹ̀yin Tọkọtaya (Éfésù 4:26, 27)
Ẹ̀yin Òbí (1 Sámúẹ́lì 17:55)
Ẹ̀yin Aṣáájú-Ọ̀nà (1 Àwọn Ọba 17:6-8, 12, 16)
Ẹ̀yin Alàgbà Ìjọ (Ìṣe 20:28-30)
Ẹ̀yin Àgbàlagbà (Dáníẹ́lì 6:10, 11; 12:13)
10:50 Orin 119 àti Ìfilọ̀
11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Nígboyà, Kì Í Ṣe Àwọn Ojo!
Má Tẹ̀ Lé Àwọn Ìjòyè Mẹ́wàá, Tẹ̀ Lé Jóṣúà àti Kálébù (Númérì 14:7-9)
Má Tẹ̀ Lé Àwọn Aráàlú Mérósì, Tẹ̀ Lé Jáẹ́lì (Àwọn Onídàájọ́ 5:23)
Má Tẹ̀ Lé Àwọn Wòlíì Èké, Tẹ̀ Lé Mikáyà (1 Àwọn Ọba 22:14)
Má Tẹ̀ Lé Úríjà, Tẹ̀ Lé Jeremáyà (Jeremáyà 26:21-23)
Má Tẹ̀ Lé Ọ̀dọ́kùnrin Ọlọ́rọ̀ Tó Jẹ́ Alákòóso, Tẹ̀ Lé Pọ́ọ̀lù (Máàkù 10:21, 22)
11:45 ÌRÌBỌMI: “Àwa Kì Í Ṣe Irú Àwọn Tí Ń Fà Sẹ́yìn”! (Hébérù 10:35, 36, 39; 11:30, 32-34, 36; 1 Pétérù 5:10)
12:15 Orin 38 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 111
1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Kọ́ Ìgboyà Lára Àwọn Ohun Tí Ọlọ́run Dá
Kìnnìún (Míkà 5:8)
Ẹṣin (Jóòbù 39:19-25)
Asín Igbó (Sáàmù 91:3, 13-15)
Ẹyẹ Akùnyùnmù (1 Pétérù 3:15)
Erin (Òwe 17:17)
2:40 Orin 60 àti Ìfilọ̀
2:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Bí Àwọn Ará Wa Ṣe Ń Fi Hàn Pé Àwọn Nígboyà ní . . .
Áfíríkà (Mátíù 10:36-39)
Éṣíà (Sekaráyà 2:8)
Yúróòpù (Ìṣípayá 2:10)
Amẹ́ríkà Ti Àríwá (Aísáyà 6:8)
Oceania (Sáàmù 94:14, 19)
Amẹ́ríkà Ti Gúúsù (Sáàmù 34:19)
4:15 Jẹ́ Onígboyà àmọ́ Má Ṣe Dá Ara Rẹ Lójú Jù! (Òwe 3:5, 6; Aísáyà 25:9; Jeremáyà 17:5-10; Jòhánù 5:19)
4:50 Orin 3 àti Àdúrà Ìparí