ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm18 ojú ìwé 6-7
  • Sunday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sunday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2018
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2025
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2018
CO-pgm18 ojú ìwé 6-7
Jésù jí ọmọbìnrin Jáírù dìde

Sunday

“Jẹ́ onígboyà, sì jẹ́ kí ọkàn-àyà rẹ jẹ́ alágbára. Bẹ́ẹ̀ ni, ní ìrètí nínú Jèhófà”​—SÁÀMÙ 27:14

ÒWÚRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 73 àti Àdúrà

  • 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Ohun Tó Máa Ṣẹlẹ̀ Lọ́jọ́ Iwájú Tó Gba Pé Ká Ní Ìgboyà

    • Ìkéde “Àlàáfíà àti Ààbò!” (1 Tẹsalóníkà 5:​2, 3)

    • Ìparun Bábílónì Ńlá (Ìṣípayá 17:16, 17)

    • Ìkéde Tó Dà Bí Òkúta Yìnyín (Ìṣípayá 16:21)

    • Gọ́ọ̀gù Ti Ilẹ̀ Mágọ́gù Máa Gbéjà Ko Àwọn Èèyàn Ọlọ́run (Ìsíkíẹ́lì 38:​10-12, 14-16)

    • Amágẹ́dọ́nì (Ìṣípayá 16:14, 16)

    • Iṣẹ́ Àtúnkọ́ Ńlá (Aísáyà 65:21)

    • Ìdánwò Ìkẹyìn (Ìṣípayá 20:3, 7, 8)

  • 11:10 Orin 8 àti Ìfilọ̀

  • 11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Báwo Ni Ìrètí Àjíǹde Ṣe Ń Jẹ́ Ká Ní Ìgboyà? (Máàkù 5:35-42; Lúùkù 12:4, 5; Jòhánù 5:28, 29; 11:11-14)

  • 11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 12:20 Orin 151 àti Àkókò Ìsinmi

Jónà ń rìn lọ sílùú Nínéfè

Ọ̀SÁN

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 5

  • 1:50 FÍÌMÙ: Ìtàn Jónà​—Ẹ̀kọ́ Nípa Ìgboyà àti Àánú (Jónà 1-4)

  • 2:40 Orin 71 àti Ìfilọ̀

  • 2:50 Àwọn Tó Wà Pẹ̀lú Wa Pọ̀ Ju Awọn Tó Wà Lòdì Sí Wa Lọ! (Diutarónómì 7:17, 21; 28:2; 2 Àwọn Ọba 6:16; 2 Kíróníkà 14:9-11; 32:7, 8, 21; Aísáyà 41:10-13)

  • 3:50 Orin Ìparí àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́