ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm19 ojú ìwé 6-7
  • Sunday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Sunday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2020
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2017
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2025
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
CO-pgm19 ojú ìwé 6-7
Ọba Jòsáyà ń ka àkájọ ìwé kan

Sunday

‘Ẹ DÚRÓ NÍNÚ ÌFẸ́ ỌLỌ́RUN’​—JÚÙDÙ 21

ÒWÚRỌ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin 106 àti Àdúrà

  • 9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Má Gbàgbé Ohun Tí Ìfẹ́ Máa Ń Ṣe

    • Ìfẹ́ Máa Ń Ní Sùúrù àti Inú Rere (1 Kọ́ríńtì 13:4)

    • Ìfẹ́ Kì Í Jowú; Kì Í Fọ́nnu (1 Kọ́ríńtì 13:4)

    • Kì Í Gbéra Ga; Kì Í Hùwà Tí Kò Bójú Mu (1 Kọ́ríńtì 13:4, 5)

    • Kì Í Wá Ire Tirẹ̀ Nìkan; Kì Í Tètè Bínú (1 Kọ́ríńtì 13:5)

    • Kì Í Di Èèyàn Sínú; Kì Í Yọ̀ Lórí Àìṣòdodo (1 Kọ́ríńtì 13:5, 6)

    • Ó Máa Ń Yọ̀ Lórí Òtítọ́; Ó Máa Ń Mú Ohun Gbogbo Mọ́ra (1 Kọ́ríńtì 13:6, 7)

    • Ó Máa Ń Gba Ohun Gbogbo Gbọ́; Ó Máa Ń Retí Ohun Gbogbo (1 Kọ́ríńtì 13:7)

    • Ó Máa Ń Fara Da Ohun Gbogbo; Ìfẹ́ Kì Í Yẹ̀ Láé (1 Kọ́ríńtì 13:7, 8)

  • 11:10 Orin 150 and àti Ìfilọ̀

  • 11:20 ÀSỌYÉ FÚN GBOGBO ÈNÌYÀN: Ibo Lo Ti Lè Rí Ìfẹ́ Tòótọ́ Nínú Ayé Tó Kún fún Ìkórìíra Yìí? (Jòhánù 13:34, 35)

  • 11:50 Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́

  • 12:20 Orin 1 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀SÁN

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 124

  • 1:50 FÍÌMÙ: Ìtàn Jòsáyà: Nífẹ̀ẹ́ Jèhófà; Kórìíra Ohun Búburú—Apá Kejì (2 Àwọn Ọba 22:3-20; 23:1-25; 2 Kíróníkà 34:3-33; 35:1-19)

  • 2:20 Orin “Jẹ́ Kí N Ní Ìgboyà” àti Ìfilọ̀

  • 2:30 “Fara Balẹ̀ Kíyè Sí Àwọn Ohun Tí Jèhófà Ṣe Nítorí Ìfẹ́ Rẹ̀ Tí Kì Í Yẹ̀” (Sáàmù 107:43; Éfésù 5:1, 2)

  • 3:30 Orin Tuntun àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́