Friday
“Fún wa ní ìgbàgbọ́ sí i”—Lúùkù 17:5
ÀÁRỌ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 5 àti Àdúrà
9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Báwo Ni Ìgbàgbọ́ Ṣe Lágbára Tó? (Mátíù 17:19, 20; Hébérù 11:1)
10:10 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Ìdí Tá A Fi Gbà Gbọ́ Pé . . .
• Ọlọ́run Wà (Éfésù 2:1, 12; Hébérù 11:3)
• Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run Ni Bíbélì (Àìsáyà 46:10)
• Ìlànà Ọlọ́run Ló Dáa Jù (Àìsáyà 48:17)
• Ọlọ́run Nífẹ̀ẹ́ Wa (Jòhánù 6:44)
11:05 Orin 37 àti Ìfilọ̀
11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: Ìgbàgbọ́ Mú Kí Nóà Ṣègbọràn (Jẹ́nẹ́sísì 6:1–8:22; 9:8-16)
11:45 ‘Ẹ Ní Ìgbàgbọ́, Ẹ Má sì Ṣiyèméjì’ (Mátíù 21:21, 22)
12:15 Orin 118 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀SÁN
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 2
1:50 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Jẹ́ Kí Àwọn Ohun Tí Jèhófà Dá Mú Kí Ìgbàgbọ́ Rẹ Lágbára Sí I
• Àwọn Ìràwọ̀ (Àìsáyà 40:26)
• Òkun (Sáàmù 93:4)
• Igbó Kìjikìji (Sáàmù 37:10, 11, 29)
• Ẹ̀fúùfù àti Omi (Sáàmù 147:17, 18)
• Àwọn Ẹ̀dá Inú Òkun (Sáàmù 104:27, 28)
• Ara Àwa Èèyàn (Àìsáyà 33:24)
2:50 Orin 148 àti Ìfilọ̀
3:00 Àwọn Iṣẹ́ Agbára Jèhófà Ń Mú Kí Ìgbàgbọ́ Wa Lágbára (Àìsáyà 43:10; Hébérù 11:32-35)
3:20 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn Tó Nígbàgbọ́, Kì Í Ṣe Àwọn Tí Kò Nígbàgbọ́
• Tẹ̀ Lé Ébẹ́lì, Má Tẹ̀ Lé Kéènì (Hébérù 11:4)
• Tẹ̀ Lé Énọ́kù, Má Tẹ̀ Lé Lámékì (Hébérù 11:5)
• Tẹ̀ Lé Nóà, Má Tẹ̀ Lé Àwọn Aládùúgbò Rẹ̀ (Hébérù 11:7)
• Tẹ̀ Lé Mósè, Má Tẹ̀ Lé Fáráò (Hébérù 11:24-26)
• Tẹ̀ Lé Àwọn Ọmọ Ẹ̀yìn Jésù, Má Tẹ̀ Lé Àwọn Farisí (Ìṣe 5:29)
4:15 Báwo Lo Ṣe Lè ‘Máa Dán Ara Rẹ Wò Bóyá O Wà Nínú Ìgbàgbọ́’? (2 Kọ́ríńtì 13:5, 11)
4:50 Orin 119 àti Àdúrà Ìparí