ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • CO-pgm23 ojú ìwé 2-8
  • Friday

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Friday
  • Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2023
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Saturday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2023
  • Sunday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2024
  • Friday
    Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Àgbègbè ti Ọdún 2019
Àwọn Míì
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ Àpéjọ Agbègbè ti Ọdún 2023
CO-pgm23 ojú ìwé 2-8
Àwòrán: Àwọn nǹkan tá a máa gbádùn lọ́jọ́ Friday. 1. Ọba Sọ́ọ̀lù wọnú àhámọ́ tí Dáfídì àtàwọn ọkùnrin ẹ̀ sá pamọ́ sí. 2. Tọkọtaya kan ń wàásù. 3. Àwọn ẹyẹ àtàwọn ọmọ wọn.

Ẹyẹ Penguin: Nípasẹ̀ ìyọ̀ǹda John R. Peiniger

Friday

“Ìfẹ́ máa ń ní sùúrù”​—1 Kọ́ríńtì 13:4

Àárọ̀

  • 9:20 Fídíò Orin

  • 9:30 Orin No. 66 àti Àdúrà

  • 9:40 Ọ̀RỌ̀ ALÁGA: Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa “Ní Sùúrù”? (Jémíìsì 5:7, 8; Kólósè 1:9-11; 3:12)

  • 10:10 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: “Ohun Gbogbo Ni Àkókò Wà Fún”

    • • Máa Ronú Nípa Bí Jèhófà Ṣe Máa Ń Fara Balẹ̀ Ṣe Nǹkan (Oníwàásù 3:1-8, 11)

    • • Ó Máa Ń Gba Àkókò Káwa Àtẹnì Kan Tó Di Ọ̀rẹ́ Tímọ́tímọ́ (Òwe 17:17)

    • • Ó Máa Ń Gba Àkókò Kí Òtítọ́ Tó Jinlẹ̀ Lọ́kàn Èèyàn (Máàkù 4:26-29)

    • • Ó Máa Ń Gba Àkókò Kọ́wọ́ Wa Tó Lè Tẹ Àfojúsùn Wa (Oníwàásù 11:4, 6)

  • 11:05 Orin 143 àti Ìfilọ̀

  • 11:15 BÍBÉLÌ KÍKÀ BÍ ẸNI ṢE ERÉ ÌTÀN: Dáfídì Fi Sùúrù Dúró De Jèhófà (1 Sámúẹ́lì 24:2-15; 25:1-35; 26:2-12; Sáàmù 37:1-7)

  • 11:45 Ṣé O Mọyì Bí Sùúrù Ọlọ́run Ṣe Pọ̀ Tó? (Róòmù 2:4, 6, 7; 2 Pétérù 3:8, 9; Ìfihàn 11:18)

  • 12:15 Orin 147 àti Àkókò Ìsinmi

Ọ̀sán

  • 1:35 Fídíò Orin

  • 1:45 Orin 17

  • 1:50 Máa Ṣe Sùúrù Bíi ti Jésù (Hébérù 12:2, 3)

  • 2:10 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Àwọn tí Jèhófà Bù Kún Torí Pé Wọ́n Ní Sùúrù

    • • Ábúráhámù àti Sérà (Hébérù 6:12)

    • • Jósẹ́fù (Jẹ́nẹ́sísì 39:7-9)

    • • Jóòbù (Jémíìsì 5:11)

    • • Módékáì àti Ẹ́sítà (Ẹ́sítà 4:11-16)

    • • Sekaráyà àti Èlísábẹ́tì (Lúùkù 1:6, 7)

    • • Pọ́ọ̀lù (Ìṣe 14:21, 22)

  • 3:10 Orin 11 àti Ìfilọ̀

  • 3:20 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: Àwọn Nǹkan tí Jèhófà Dá Kọ́ Wa Pé Ó Máa Ń Ṣe Nǹkan Lásìkò

    • • Àwọn Ewéko (Mátíù 24:32, 33)

    • • Àwọn Ẹ̀dá Inú Òkun (2 Kọ́ríńtì 6:2)

    • • Àwọn Ẹyẹ (Jeremáyà 8:7)

    • • Àwọn Kòkòrò (Òwe 6:6-8; 1 Kọ́ríńtì 9:26)

    • • Àwọn Ẹranko (Oníwàásù 4:6; Fílípì 1:9, 10)

  • 4:20 “Ẹ Ò Mọ Ọjọ́ Tàbí Wákàtí Náà” (Mátíù 24:36; 25:13, 46)

  • 4:55 Orin 27 àti Àdúrà Ìparí

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́