Saturday
“Ẹ máa mú sùúrù fún gbogbo èèyàn”—1 Tẹsalóníkà 5:14
Àárọ̀
9:20 Fídíò Orin
9:30 Orin 58 àti Àdúrà
9:40 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: ‘À Ń Dámọ̀ràn Ara Wa Bí Òjíṣẹ́ Ọlọ́run . . . Bá A Ṣe Ń Mú Sùúrù’
• Tá A Bá Ń Wàásù (Ìṣe 26:29; 2 Kọ́ríńtì 6:4, 6)
• Tá A Bá Ń Kọ́ni (Jòhánù 16:12)
• Tá A Bá Ń Fún Ara Wa Níṣìírí (1 Tẹsalóníkà 5:11)
• Tá A Bá Jẹ́ Alàgbà (2 Tímótì 4:2)
10:30 Ẹ Máa Mú Sùúrù Fáwọn Èèyàn Bí Jèhófà Ṣe Ń Mú Sùúrù fún Yín! (Mátíù 7:1, 2; 18:23-35)
10:50 Orin 138 àti Ìfilọ̀
11:00 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: ‘Ẹ Ní Sùúrù, Kí Ẹ sì Máa Fara Dà Á fún Ara Yín Nínú Ìfẹ́’
• Àwọn Mọ̀lẹ́bí Wa tí Kò Sin Jèhófà (Kólósè 4:6)
• Ọkọ Tàbí Aya Rẹ (Òwe 19:11)
• Àwọn Ọmọ Rẹ (2 Tímótì 3:14)
• Àwọn Àgbàlagbà Tàbí Àwọn tí Ara Wọn Ò Le Nínú Ìdílé (Hébérù 13:16)
11:45 ÌRÌBỌMI: Sùúrù Jèhófà Máa Jẹ́ Ká Rí Ìgbàlà! (2 Pétérù 3:13-15)
12:15 Orin 75 àti Àkókò Ìsinmi
Ọ̀sán
1:35 Fídíò Orin
1:45 Orin 106
1:50 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ṣọ́ra fún Ìgbádùn Ojú Ẹsẹ̀? (1 Tẹsalóníkà 4:3-5; 1 Jòhánù 2:17)
2:15 ÀPÍNSỌ ÀSỌYÉ: ‘Ó Sàn Kéèyàn Ní Sùúrù Ju Pé Kó Máa Gbéra Ga’
• Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Ébẹ́lì, Má Tẹ̀ Lé ti Ádámù (Oníwàásù 7:8)
• Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jékọ́bù, Má Tẹ̀ Lé ti Ísọ̀ (Hébérù 12:16)
• Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Mósè, Má Tẹ̀ Lé ti Kórà (Nọ́ńbà 16:9, 10)
• Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Sámúẹ́lì, Má Tẹ̀ Lé ti Sọ́ọ̀lù (1 Sámúẹ́lì 15:22)
• Tẹ̀ Lé Àpẹẹrẹ Jónátánì, Má Tẹ̀ Lé ti Ábúsálómù (1 Sámúẹ́lì 23:16-18)
3:15 Orin 87 àti Ìfilọ̀
3:25 FÍDÍÒ: “Fi Ọ̀nà Rẹ Lé Jèhófà Lọ́wọ́”—Apá 1 (Sáàmù 37:5)
3:55 “Nígbà Tí Wọ́n Ń Ṣe Inúnibíni sí Wa, À Ń Fara Dà Á Pẹ̀lú Sùúrù” (1 Kọ́ríńtì 4:12; Róòmù 12:14, 21)
4:30 Orin 79 àti Àdúrà Ìparí