ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • km 12/15 ojú ìwé 4
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Ohun Tó O Lè Sọ Nípa Àwọn Ìwé Ìròyìn
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2010
Àwọn Míì
Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2015
km 12/15 ojú ìwé 4

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Ilé Ìṣọ́ January 1

“Ǹjẹ́ o rò pé ayé yìí máa dára gan-an tí gbogbo wa bá ń tẹ̀ lé ìlànà yìí? [Ka Hébérù 13:​18, kó o sì jẹ́ kó fèsì.] Bíbélì gbà wá níyànjú pé ká jẹ́ olóòótọ́ nínú ohun gbogbo. Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ ti oṣù yìí sọ̀rọ̀ nípa bí a ṣe lè jẹ́ olóòótọ́ ní gbogbo apá ìgbésí ayé wa.”

Ji! January–February

“Ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń ṣe kàyéfì nípa ìwà àgàbàgebè àtàwọn ẹ̀kọ́ èké tó wà nínú ọ̀pọ̀ ẹ̀sìn. Kí lo rò pé ó máa ṣẹlẹ̀ sí ìsìn lọ́jọ́ iwájú? [Jẹ́ kó fèsì.] Ìwé ìròyìn yìí sọ̀rọ̀ nípa àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì pàtàkì kan tó wà nínú ìwé Ìṣípayá, èyí tó sọ nípa bí àwọn èèyàn á ṣe kúrò nínú ìsìn èké àti bí Ọlọ́run ṣe máa pa ìsìn èké run pátápátá.”

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́