ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 April ojú ìwé 6
  • Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • BÁWO LA ṢE LÈ FI HÀN PÉ A NÍFẸ̀Ẹ́ ÀWỌN ARÁ WA . . .
  • Máa Fojú Sọ́nà fún Jèhófà
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2006
  • Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Ọ̀nà Ìgbésí Ayé Tí Ọlọ́run Fẹ́” ti 1998
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1998
  • A Máa Gbádùn Ìtura Nípa Tẹ̀mí fún Ọjọ́ Mẹ́ta
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2011
  • Àpéjọpọ̀ Àgbègbè “Àwọn Ońṣẹ́ Àlàáfíà Ọlọ́run” ti 1996
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—1996
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 April ojú ìwé 6

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè

Ìfẹ́ tá a ní fún Ọlọ́run àti àwọn aládùúgbò wa ló ń darí wa nígbà gbogbo àti ní pàtàkì, nígbà àpéjọ àgbègbè. (Mt 22:37-39) Kọ́ríńtì Kìíní 13:4-8 sọ àwọn ohun tí ìfẹ́ máa ń ṣe, ó ní: “Ìfẹ́ a máa ní ìpamọ́ra àti inú rere. . . . [Ìfẹ́] kì í hùwà lọ́nà tí kò bójú mu, kì í wá àwọn ire tirẹ̀ nìkan, a kì í tán an ní sùúrù. . . . Ìfẹ́ kì í kùnà láé.” Bí o ṣe ń wo fídíò náà Àwọn Ohun Tó Yẹ Ká Fi Sọ́kàn Nípa Àpéjọ Àgbègbè, ronú nípa onírúurú ọ̀nà tí wàá gbà fi hàn pé o nífẹ̀ẹ́ àwọn tó wá sí àpéjọ àgbègbè.

BÁWO LA ṢE LÈ FI HÀN PÉ A NÍFẸ̀Ẹ́ ÀWỌN ARÁ WA . . .

  • tá a bá ń gba àyè ìjókòó?

    Ìdílé kan tó jókòó pa pọ̀ nígbà àpéjọ, kò sí àyè tó ṣófo láàárín wọn
  • tí ohùn orin bá ti fẹ́ bẹ̀rẹ̀?

    Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa ń jókòó, wọ́n sì ń tẹ́tí sí ohùn orin kí ìtòlẹ́sẹẹsẹ àpéjọ àgbègbè tó bẹ̀rẹ̀
  • tá a bá wà níbi tá a dé sí?

    Ìdílé kan wa ọkọ̀ dé òtẹ́ẹ̀lì
  • tá a bá ń yọ̀ǹda ara wa láti ṣiṣẹ́ ìyọ̀ǹda ara ẹni?

    Ibi tí wọ́n ti máa ṣe àpéjọ
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́