ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 April ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • JÍ!
  • JÍ!
  • Bíbélì Fi Kọ́ni
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 April ojú ìwé 1
Àwọn tó wá sí àpéjọ àgbáyé ti àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ọdún 2014 ní New Jersey, lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Àwọn ará wà ní àpéjọ àgbáyé ti ọdún 2014 ní New Jersey, lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

JÍ!

Ìwé ìròyìn Jí!, No. 2 2016 | Ṣé Ìwé Dáradára Kan Lásán Ni Bíbélì?

Fi ìwé lọni: Mo mú ìwé ìròyìn Jí! tó ṣẹ̀ṣẹ̀ jáde yìí wá fún yín

Béèrè ìbéèrè: Ẹ wo ìbéèrè tó wà lójú ìwé 2 yìí. Ẹ jọ̀wọ́, kí lèrò yín nípa rẹ̀?

Ka Bíbélì: Lk 7:35

Àpilẹ̀kọ yìí sọ̀rọ̀ nípa bí ohun tá a kà yìí ṣe fi hàn pé ìwé ọgbọ́n ni Bíbélì.

JÍ!

Béèrè ìbéèrè: Ǹjẹ́ ẹ gbà pé ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó yẹ ká máa fi sílò ni ọ̀rọ̀ yìí?

Ka Bíbélì: Mt 6:34

Fi ìwé lọni: [Ṣí ìwé ìròyìn náà sí àpilẹ̀kọ tó ní àkorí náà “Ìwòye Bíbélì​—Àníyàn.”] Àpilẹ̀kọ yìí jẹ́ ká mọ bí Bíbélì ṣe lè ràn wá lọ́wọ́ láti borí àníyàn.

Bíbélì Fi Kọ́ni

Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-⁠an?

Béèrè ìbéèrè: Ọ̀pọ̀ àwọn tó gbà pé Ọlọ́run wà ló máa ń fẹ́ sún mọ́ ọn. Ǹjẹ́ ẹ mọ̀ pé Bíbélì sọ pé ká sún mọ́ Ọlọ́run?

Ka Bíbélì: Jak 4:8a

Fi ìwé lọni: A ṣe ìwé yìí ká lè fi kẹ́kọ̀ọ́ sí i nípa Ọlọ́run nínú Bíbélì. [Fi orí 1 han onílé nínú ìwé Bíbélì Fi Kọ́ni.]

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́