ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 June ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • JÍ!
  • JÍ!
  • ÀWỌN ÌWÉ ÀṢÀRÒ KÚKÚRÚ
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 June ojú ìwé 1
Àwọn akéde ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú lọ ọkùnrin kan nílùú Málítà

Àwọn akéde ń fi ìwé àṣàrò kúkúrú lọni nílùú Málítà

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

JÍ!

Jí! No. 3 2016 | Bá A Ṣe Borí Ìṣòro Èdè

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn Jí! yìí sọ̀rọ̀ nípa kókó pàtàkì kan. [Fún onílé ní ẹ̀dà kan.]

Béèrè ìbéèrè: Ǹjẹ́ o mọ̀ pé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń túmọ̀ àwọn ìwé wa sí ohun tó ju ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀rin ó lé àádọ́ta [750] èdè lọ?

Ka Bíbélì: Iṣi 14:6

JÍ!

Béèrè ìbéèrè: Ǹjẹ́ ẹ rò pé ìlànà yìí lè ran àwọn tọkọtaya lọ́wọ́ láti yanjú àìgbọ́ra-ẹni-yé tó bá wáyé láàárín wọn?

Ka Bíbélì: Jak 1:19

Fi ìwé lọni: [Fi àpilẹ̀kọ tó bẹ̀rẹ̀ lójú ìwé 10 han onílé.] Àpilẹ̀kọ yìí sọ àwọn ìlànà Bíbélì míì lórí kókó yìí.

ÀWỌN ÌWÉ ÀṢÀRÒ KÚKÚRÚ

Ìwé àṣàrò kúkúrú

Béèrè ìbéèrè: Ẹ jọ̀wọ́, ẹ wo ìbéèrè yìí. [Ka ìbéèrè tó wà níwájú ìwé àṣàrò kúkúrú náà àti onírúurú ìdáhùn tó wà níbẹ̀.] Kí lèrò yín nípa rẹ̀?

Ka Bíbélì: [Èyí tó wà lójú ìwé 2 nínú ìwé àṣàrò kúkúrú náà]

Fi ìwé lọni: Ìwé yìí sọ àǹfààní tí ọ̀rọ̀ Bíbélì yìí lè ṣe fún yín.

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́