ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 38-44
Jèhófà Máa Ń Gbé Àwọn Aláìsàn Ró
Àwọn olóòótọ́ ìránṣẹ́ Ọlọ́run gbà pé Jèhófà máa ran àwọn lọ́wọ́ nígbà ìṣòro
Dáfídì ṣàìsàn gan-an
Dáfídì gba ti àwọn ẹni rírẹlẹ̀ rò
Dáfídì kò retí pé kí Jèhófà wo òun sàn lọ́nà ìyanu, àmọ́ ó bẹ Jèhófà pé kó tu òun nínú, kó fún òun lọ́gbọ́n, kó sì ran òun lọ́wọ́
Jèhófà ka Dáfídì sí ọkùnrin oníwà títọ́