ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SÁÀMÙ 92-101
Bí Àwọn Àgbàlagbà Ṣe Lè Máa Sin Jèhófà Nìṣó
Igi ọ̀pẹ máa ń lo ju ọgọ́rùn-ún ọdún lọ láyé, síbẹ̀ á ṣì máa so èso
Àwọn àgbàlagbà máa ń so èso tẹ̀mí nígbà tí wọ́n bá ń . . .
gbàdúrà fún àwọn ẹlòmíì
kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
lọ sáwọn ìpàdé ìjọ tí wọ́n sì ń kópa níbẹ̀
sọ àwọn ìrírí tí wọ́n ní fún àwọn ẹlòmíì
wàásù tọkàntọkàn