ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | LÚÙKÙ 2-3
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Àjọṣe Yín Pẹ̀lú Jèhófà Túbọ̀ Ń Lágbára Sí I?
Láti kékeré ni Jésù ti fi àpẹẹrẹ rere lélẹ̀ tó bá di ọ̀rọ̀ ká sin Jèhófà àti ká bọ̀wọ̀ fún àwọn òbí ẹni.
Ẹ̀yin ọ̀dọ́, báwo lẹ ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Jésù ní àwọn ọ̀nà yìí?