ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 July ojú ìwé 5
  • Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ǹjẹ́ Ẹ Ṣe Tán Láti Di Ìránṣẹ́ Tàbí Alàgbà?
    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba Wa—2013
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Káwa Kristẹni Máa Sapá Láti Tẹ̀ Síwájú?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ẹ̀yin Ọ̀dọ́, Ṣé Àjọṣe Yín Pẹ̀lú Jèhófà Túbọ̀ Ń Lágbára Sí I?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2018
  • Àwọn Ìránṣẹ́ Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ń Ṣe Ìjọ Láǹfààní
    A Ṣètò Wa Láti Ṣe Ìfẹ́ Jèhófà
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 July ojú ìwé 5
Arákùnrin kan tó jẹ́ ọ̀dọ́ ń gbé maikirofóònù nínú ìpàdé, ó ń ṣe ìdákẹ́kọ̀ọ́, ó sì ń ti arábìnrin àgbàlagbà kan lórí àga arọ

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | 1 TÍMÓTÌ 1-3

Iṣẹ́ Rere Ni Kó O Máa Lé

3:1, 13

Àtikékeré ló ti dáa jù káwọn arákùnrin ti máa ran ìjọ lọ́wọ́. Èyí máa ràn wọ́n lọ́wọ́ láti gba ìdálẹ́kọ̀ọ́, bí wọ́n sì ṣe ń dàgbà sí i, ó máa túbọ̀ ṣe kedere pé wọ́n ti ń tóótun láti di ìránṣẹ́ iṣẹ́ òjíṣẹ́. (1Ti 3:10) Báwo ni arákùnrin kan ṣe lè máa lé iṣẹ́ rere? Wọ́n lè ṣe bẹ́ẹ̀ tí wọ́n bá ń fi àwọn ànímọ́ yìí sílò:

  • Máa yọ̀ǹda ara rẹ.​—km 7/13 2-3 ¶2

  • Jẹ́ ẹni tẹ̀mí.​—km 7/13 3 ¶3

  • Jẹ́ olóòótọ́ àti ẹni tó ṣeé fọkàn tán.​—km 7/13 3 ¶4

Alàgbà kan ń bá ọ̀dọ́kùnrin kan sọ̀rọ̀ bó ṣe ń dá a lẹ́kọ̀ọ́ kó lè máa ṣiṣẹ́ sìn nínú ìjọ
    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́