ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb16 October ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • JÍ!
  • MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI
  • ÌWÉ ÌKÉSÍNI SÍ ÀWỌN ÌPÀDÉ ÌJỌ (inv)
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
mwb16 October ojú ìwé 1
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń fún ẹnì kan ní ìwé ìkésíni sí ìpàdé ìjọ

Wọ́n ń pe àwọn èèyàn wá sí ìpàdé

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

JÍ!

Jí! No. 5 2016 | Ṣé Jésù Wà Lóòótọ́?

Béèrè ìbéèrè: Àwọn kan ń ṣiyè méjì pé bóyá ni Jésù wà, ó sì dá àwọn míì lójú gbangba pé Jésù wà. Àwọn míì sì sọ pé kò sí bí èèyàn ṣe lè mọ̀ bóyá Jésù wà tàbí kò sí. Kí lèrò yín?

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn Jí! yìí sọ àwọn ẹ̀rí tó fi hàn pé Jésù wà lóòótọ́.

MÁA FI ÒTÍTỌ́ KỌ́NI

Bíbélì tó wà ní ṣíṣí

Béèrè ìbéèrè: Kí ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn tó ti kú?

Ka Bíbélì: Jo 11:​11-14

Òtítọ́: Téèyàn bá kú, ó ti tán nìyẹn. Torí náà, kò sídìí láti máa bẹ̀rù pé èèyàn máa lọ jìyà níbì kan. Jésù sọ pé ńṣe ni ikú dà bí ìgbà téèyàn sùn. Bí Jésù ṣe jí Lásárù dìde, ó lè jí àwọn èèyàn wa tó ti kú náà dìde, kí wọ́n lè pa dà gbádùn ìgbésí ayé wọn.​—⁠Job 14:⁠14.

ÌWÉ ÌKÉSÍNI SÍ ÀWỌN ÌPÀDÉ ÌJỌ (inv)

Ìwé Ìkésíni sí Àwọn Ìpàdé Ìjọ

Fi ìwé lọni: Mo fẹ́ pè yín láti wá gbọ́ àsọyé kan tó dá lórí Bíbélì, ọ̀fẹ́ ni o. Ilé ìpàdé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ládùúgbò yín la ti máa ṣe é. [Fún un ní ìwé ìkésíni, sọ àkókò àti àdírẹ́sì ibi tẹ́ ẹ ti máa ń ṣe ìpàdé ní òpin ọ̀sẹ̀, kó o sì sọ àkòrí àsọyé tẹ́ ẹ máa gbọ́ lọ́sẹ̀ yẹn.]

Béèrè ìbéèrè: Ṣé ẹ ti lọ sí ilé ìpàdé àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà rí? [Tó bá ṣeé ṣe, fi fídíò náà Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ Nínú Gbọ̀ngàn Ìjọba? hàn án.]

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́