ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 March ojú ìwé 1
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Ìsọ̀rí
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • ILÉ ÌṢỌ́
  • KÍ NI ÌJỌBA ỌLỌ́RUN?
  • ÌWÉ ÌKÉSÍNI SÍBI ÌRÀNTÍ IKÚ KRISTI
  • KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2016)
  • Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 March ojú ìwé 1
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní Albania ń fún ọkùnrin kan ní ìwé ìkésíni sí Ìrántí Ikú Jésù

Wọ́n ń pe àwọn èèyàn síbi Oúnjẹ Alẹ́ Olúwa ní Albania

Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò

ILÉ ÌṢỌ́

Ilé Ìṣọ́ No. 2 2017 | Ṣé Wàá Gba Ẹ̀bùn Ọlọ́run Tó Dára Jù?

Béèrè ìbéèrè: Kí lẹ rò pé ó jẹ́ ẹ̀bùn tó dára jù lọ tí Ọlọ́run tíì fún wa?

Ka Bíbélì: Jo 3:16

Fi ìwé lọni: Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí sọ ìdí tí Ọlọ́run fi rán Jésù wá sáyé àti bá a ṣe lè fi hàn pé a mọ rírì ẹ̀bùn náà.

KÍ NI ÌJỌBA ỌLỌ́RUN?

Kí Ni Ìjọba Ọlọ́run?

Béèrè ìbéèrè: [Fi iwájú ìwé àṣàrò kúkúrú náà hàn án.] Kí ni èrò yín nípa ìbéèrè yìí? Ṣé ọkàn èèyàn ni Ìjọba Ọlọ́run wà? àbí àkànlò èdè ni? àbí ìjọba kan ní ọ̀run?

Ka Bíbélì: Da 2:44; Ais 9:6

Fi ìwé lọni: Ìwé àṣàrò kúkúrú yìí jẹ́ ká mọ àǹfààní tí Ìjọba Ọlọ́run máa ṣe fún wa.

ÌWÉ ÌKÉSÍNI SÍBI ÌRÀNTÍ IKÚ KRISTI

Ìwé Ìkésíni Síbi Ìràntí Ikú Jésù 2017

Fi ìwé lọni: À ń pe àwọn èèyàn wá síbi ìṣẹ̀lẹ̀ pàtàkì kan. [Fún un ní ìwé ìkésíni.] Ní April 11, ọ̀pọ̀ èèyàn jákèjádò ayé máa pé jọ láti ṣe ìrántí ikú Jésù, wọ́n á sì gbọ́ àsọyé kan tó dá lórí Bíbélì nípa bí ikú Jésù ṣe lè ṣe wá láǹfààní, ọ̀fẹ́ sì ni. Wàá rí àkókò àti ibi tá a ti máa ṣe ìpàdé náà nínú ìwé yìí. A ó máa retí yín o.

KỌ Ọ̀NÀ ÌGBỌ́RỌ̀KALẸ̀ RẸ

Wo àwọn ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tá a fi ṣe àpẹẹrẹ yìí, kó o sì kọ ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ tìrẹ.

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́