ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb17 June ojú ìwé 4
  • Ẹ̀mí Ìdúródeni Ń Jẹ́ Ká Ní Ìfaradà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ẹ̀mí Ìdúródeni Ń Jẹ́ Ká Ní Ìfaradà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Ẹ Fi Ẹ̀mí Ìdúródeni Hàn!
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2000
  • Wọ́n Láyọ̀ Láti Dúró De Jèhófà
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • Àwọn Kókó Pàtàkì Látinú Ìwé Ìdárò
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2007
  • “Ọkàn Rẹ Yóò . . . Tẹ̀ Ba Mọ́lẹ̀ Lórí Mi”
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2012
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Àwa Kristẹni​—Ìwé Ìpàdé (2017)
mwb17 June ojú ìwé 4

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌDÁRÒ 1-5

Ẹ̀mí Ìdúródeni Ń Jẹ́ Ká Ní Ìfaradà

Kí ló ran Jeremáyà lọ́wọ́ tó fi fara da ìṣòro tó lágbára gan-an, tí kò sì ṣìwà hù?

3:​20, 21, 24, 26, 27

  • Ọkàn rẹ̀ balẹ̀ pé Jèhófà máa “tẹ̀ ba mọ́lẹ̀” nítorí àwọn tó ti ronú pìwà dà lára àwọn èèyàn Ọlọ́run, ó sì máa mú ìbànújẹ́ kúrò lọ́kàn wọn

  • Ó ti kọ́ láti “ru àjàgà ní ìgbà èwe rẹ̀.” Tí ẹnì kan bá ti bẹ̀rẹ̀ sí í fara da àdánwò ìgbàgbọ́ láti ìgbà ọ̀dọ́, ńṣe ni èyí á mú kó rọrùn fún un láti kojú àwọn ìṣòro tó ṣì ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú

Jeremáyà ń gbàdúrà; wọ́n kó àwọn tó ń gbé ní Jerúsálẹ́mù lọ sí ìgbèkùn

Báwo ni mo ṣe lè múra sílẹ̀ de àwọn ìṣòro tó ń bọ̀ lọ́jọ́ iwájú?

Báwo ni mo ṣe lè fi ẹ̀mí ìdúródeni hàn?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́