ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌSÍKÍẸ́LÌ 15-17
Ṣé O Máa Ń Mú Ìlérí Rẹ Ṣẹ?
Ìlérí wo ni Ọba Sedekáyà kò mú ṣẹ?
Kí ló ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tí kò mú ìlérí náà ṣẹ?
Àwọn ìlérí àti àdéhùn wo ni mo ti ṣe?
Kí ló lè ṣẹlẹ̀ tí mi ò bá mú ìlérí tàbí àdéhùn náà ṣẹ?
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.