ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 4-6
Ṣé Ò Ń Sin Jèhófà Láìyẹsẹ̀?
Àdúrà wà lára nǹkan tẹ̀mí tí Dáníẹ́lì máa ń ṣe déédéé. Kò gbà kí àṣẹ ọba tàbí ohunkóhun míì dí ìjọsìn òun lọ́wọ́
Kí ni àwọn nǹkan tẹ̀mí tó yẹ ká máa ṣe déédéé?
Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.
Má bínú, fídíò yìí kò jáde.
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | DÁNÍẸ́LÌ 4-6
Kí ni àwọn nǹkan tẹ̀mí tó yẹ ká máa ṣe déédéé?